Èdè Yorùbá : akanlo ede ati itunmo re

[

Class: Pry three

Subject: Yoruba Studies

Akole: akanlo ede ati itunmo re

 1. Se aya gbangba!
  Itumo: ki eniyan doju ko isoro lai beru
 2. Ya apa!
  Itumo: ki eniyan ma mọ itoju owo tabi ohun ti a fi owo ra
 3. Edun arinle!
  Itumo: eni ti o ti lowo ri sugbon ti opa da rago tàbí kushe
 4. Fi aake kori!
  Itumo: ki eniyan ko jale lati se nkan
 5. Fi ìgbà gba ga..
  Itumo: idije,ki ẹniyan  koju ara won lati dan agbara won woo

Ise kilaasi
So itumo awon akanlo ede wonyii

 1. Se aya gbangba
 2. Edu arinle
 3. Fi ìgbà gba ga
 4. Ya apa
 5. Fi aake kori