Yoruba Second Term Examination Primary 3

NAME:…………………………………………………………………………………… OTITO BORI  

 

 1.   Ilu wo ni itan yii ti sele _____ (a) Ayokooto      (b) Ayedande
 2.    Kii ni ise Mosun (a) agbejoro     (b) onisowo
 3. Talo se ijanba fun Mosun? (a) Agbalagba kan   (b) Omodekunrin kan
 4.    Bawo ni won se ko ba Mosun?    (a) won ba Mosun ja        (b) won fi oja fayawo ranse si iso re  
 5.    Bawo ni Mosun se bo ninu isoro re? (a) awon olopaa fi sile     (b) omode kunrin kan lo tu asiri    

 

 

ALO APAMO  

 

 1.    Alo o, alo o, opo baba alo kan laelae, opo baba alo kan laelae, ojo to ba de fila pupa ni iku de ba a o, kini o  (a) abela      (b) omorogun    
 2.    Alo o, alo o, ikoko rugudu feyin tigbo, kini o (a) ijapa        (b) igbin
 3. Alo o, alo o, kini koja niwaju oba ti ko ki oba, kini o (a) agbara    (b) sigidi
 4. Alo o, alo o, awe obi kana je doyo, kini o    (a) enu                         (b) ahon
 5.    Alo o, alo o, yara kotopo, kiki egun, ki ni o  (a) enu     (b) ibepe  

 

 

ALO APAGBE: IJAPA ATI ERIN

 

 

 1. Kini awon oba fi maa nbo ori won laye atijo (a) eranko nla           (b) eranko wewe
 2.  Bawo ni ijapa se je si erin (a) ota        (b) ore
 3.    Ona wo ni ijapa gba mu erin wo ilu (a) o fun ni akara         (b) o fun ni robo aladun
 4.    Ileri wo ni kabiyesi se fun ijapa (a) o da ohun ini resi meji            (b) o je ijapa ni iya
 5.    Eko wo ni itan yii ko wa? (a) okowa ki a maa sora ni ile aye       (b) o kowa ki a maa sora fun awon odale ore  

 

 

SISE KANGO

 1.    Iya __________ fe din kango (a) Ayoka       (b) Adunni
 2. ________ ya agbado wa lati oko (a) Egbon  (b) Baba
 3.    Iya Adunni re agbado naa sinu ______ nla kan  (a) ikoko  (b) agba
 4.    O bu epo pupa sinu _______ (a) ina (b) agbada
 5.    Nigba ti __________ gbona daadaa (a) epo (b) omi