Yoruba

JSS 2 FIRST TERM LESSON NOTE YORUBA

  YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS TWO   ODUN IGBEKO 2016/2017 YORUBA JSSTWO ISE OOJO FUN SAA KIN-IN-NI Sise atunyewo fonoloji ede Yoruba Atunyewo awon asa ninu ise olodun kin-in-ni Atunyewo awon ewi alohun yoruba Eya gbolohun nipa ise won Asa igbeyawo ni ile Yoruba Kika iwe apileko ti ijoba yan Eya gbolohun Asa

JSS 2 THIRD TERM LESSON NOTE PLAN YORUBA

ILANA ISE FUN SAA KETA FUN OLODUN KEJI (JSS TWO) OSE KIN-IN-NI: EDE: ATUNYEWEO ISE SAA KEJI AROKO ALAPEJUWE/ONIROYIN ASA: ATUNYEWO IWA OMOLUABI LITIRESO: ATUNYEWO ISE SAA KEJI: EWI ALOHUN TO JE MO ESIN IBILE BII; IJALA, IYERE IFA, IWI EGUNGUN, abbl OSE KEJI: EDE: LETA GBEFE AWON WO NI A N KO O SI

Kiko Yoruba ni ilana Akoto Ode-Oni

OSE KEWAA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: Kiko Yoruba ni ilana Akoto Ode-Oni Iyato ti o de ba iro konsonati ninu akoto ode-oni Sipele Atijo                                Sipele Ode Oni Iddo                                    Ido Otta                                    Ota

IYATO TI O DE BA SIPELI FAWELI

OSE KESAN-AN EKA ISA:EDE AKOLE ISE: AKOTO Akoto je ona ti a n gba ko sipeli awon oro ede Yoruba sile lona to boju mu lode oni. Sipeli atijo ni ona ti a n gba ko awon oro ede Yoruba sile ki ijobe orile-ede Naijiria to fi owo si ona tuntun ti a le gba

ASA ISOMOLORUKO

OSE KEJO EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKAYE OLORO GEERE Ayoka kika-yoruba fun sekondu olodun meta akeko iwa keji, lati owo ola m. ajuwon etal (2014). Pg43. Itosona- Ka ayoka yii ki o si dahun awon ibeere to tele. Ni asale leyin ti aduke ati iya re je oka ati efo riro tan, iya re

AKAYE OLORO GEERE

OSE KEJE EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKAYE OLORO GEERE. Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yeni yekeyeke Igbese ayoka kika a.kika ati mimo ohun ti ayoka naa dale lori sise itupale ayoka ni finifinni fifi imo ede, laakaye ati iforabale ka ayoka naa sinu dida

Onka Yoruba (300 – 500)

OSE KEFA Eka Ise:- Ede  Akole ise: onka Yoruba (300-500)  Onka Yoruba lati oodunrun de Eedegbeta Figo 300 Oodunrun  305 Oodunrun ole-marun-un 310 Oodunrun ole-mewa  315 Okooleloodunrun odunarun-un  320 Okooleloodunrun  325 Okooleloodunrun ole-marun-un  330 Okooleloodunrun ole-mewaa 335 Ojileloodunrun odin marun-un  345 Ojileloodunrun ole-marun-un 350 Ojileloodunrin ole-mewaa  360 Otaleloodunrin  365 Otaleloodunrun ole-marun-un  370 Otaleloodunrun ole-mewaa 375

Onka Yoruba (101 – 300)

OSE KARUN – UN EKA ISE:    EDE AKOLE ISE:    Onka Yoruba (101 – 300) Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun.   Onka ni bi a se n siro nnkan ni ilana Yoruba.   Onka Yoruba lati ookanlelogorun-un de eedegbeta ONKA FIGO ONKA NI EDE YORUBA

Gbolohun Ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o.

OSE KERIN EKA ISE:    EDE AKOLE ISE:    Gbolohun Ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o. Gbolohun je akojopo oro ti oni oro ise ati ise ti o n je nibikibi ti o ba ti jeyo. Gbolohun Abode/Eleyo oro-ise Eyi ni gbolohun ti ko ni ju oro-ise kan lo.   Gbolohun Abode kii gun, gbolohun

EYA GBOLOHUN

OSE KETA EKA ISE:    EDE AKOLE ISE:    EYA GBOLOHUN Gbolohun Onibo Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re.   Gbolohun onibo pin si; Gbolohun onibo asaponle Gbolohun onibo asapejuwe Gbolohun onibo asodoruko   Gbolohun Onibo asaponle Eyi ni gbolohun ti a fi n se aponle ninu gbolohun nipa lilo oro atoka

AKOLE ISE EYA GBOLOHUN NIPA ISE WON

OSE KEJI EKA ISE – EDE AKOLE ISE  EYA GBOLOHUN NIPA ISE WON Gbolohun ni afo ti o kun, to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni olori iso. Eya gbolohun nipa ise won Gbolohun alalaye Gbolohun Ibeere Gbolohun ase Gbolohun ebe Gbolohun ayisodi     Gbolohun alalaye:Eyi

SISE ATUNYEWO FONOLOJI EDE YORUBA

OSE KIN – IN – NI  EKA ISE – EDE AKOLE ISE – SISE ATUNYEWO FONOLOJI EDE YORUBA Fonoloji ni eko nipa eto iro. A le saleye eko nipa eto iro labe awon ori oro wonyi ninu ede Yoruba Iro faweli Iro konsonanti  Eto silebu Ohun Ipaje Aranmo Oro ayalo Apetunpe abbl.   Atunyewo faweli

Third Term Examinations JSS 2 Yoruba

THIRD TERM IJIYA FUN IJIWE DAKO NI LILE KURO NI ILE IWE MASE KOPA NINU RE . JSS TWO – YORUBA LANGUAGE Wakati…….Wakati meji IPIN A: Akiyesi : Ka ayoka yi daadaa ki o si dahun awon ibeere isale yii. Eni a wi fun oba je o gbo “ori okere koko lawo” ni Orin ti

1st Term Examination YORUBA JSS 1

Edu Delight Tutors Subuode Gbaga Gasline Ogun State 1st Term Examination YORUBA JSS 1 IPIN A DAHUN GBOGBO IBEERE NI IPIN YII ————– ni baba n la awon Yoruba (a) Odudua (b) Orunmila (d) Obatala Nibo ni awon Yoruba ti se wa? (a) Oyo (b) meta (d) ile ife Ojo melo ni Oduduwa fi rin