Featured

FIRST TERM EXAMINATION FOR NURSERY, KG, PRIMARY AND SECONDARY SCHOOLS

FIRST TERM EXAMINATION FOR NURSERY, KG, PRIMARY AND SECONDARY SCHOOLS FIRST TERM EXAMINATION FOR NURSERY ONE NURSERY ONE FIRST TERM EXAMINATION HEALTH HABIT LETTER WORKS CRS   FIRST TERM EXAMINATION FOR NURSERY TWO NURSERY TWO FIRST TERM EXAMINATION HEALTH HABIT LETTER WORKS CRS     FIRST TERM EXAMINATION FOR KINDERGARTEN (KG) KG FIRST TERM EXAMINATION

ORUKO ABISO

Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 10     OSE KEWAA ORO-ORUKO – oriki – orisiirisii oro oruko. – ise ti oro oruko n se ninu gbolohun. – lilo oro oruko ninu gbolohun. AKOONU : – Oro –oruko ni awon oro ti won le da duro nipo oluwa, abo tabi

AKAYE ÀYỌKÀ

Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 9     OSE KESAN-AN AKAYE Akoonu Eka pataki ni akaye je ninu ede Yoruba. Akaye gba suuru lati ka, o gba iyosira ati amodaju awon koko-oro ti ibeere ba da le lori. Ayoka oloro wuuru Ayoka  le je ewi Ayoka le je asotan

AAYAN OGBUFO

Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 8 OSE KEJO AAYAN OGBUFO Aayan ogbufo ni ise titumo ede kan si ede miiran. Ki ogbufo to le kogo ja ninu itumo ede, o gbodo mo tifun tedo ede Geesi , ki o si le tusu ede Yoruba naa de isale ikoko. Kii

ÀRỌKO ONIROYIN

Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 6 OSE KEFA AROKO ONIROYIN Akoonu: Aroko Oniroyin:- je mo iroyin sise tabi itan isele ti o ti koja seyin ti o si se oju eni ti a n royin re ni sise-n-tele ninu aroko oniroyin fun elomiran ti ko si nibe. A rii

Ọ̀RỌ̀ ÀGBÀ SỌ (INDIRECT SPEECH)

Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 5 OSE KARUN – UN ORO – AGBASO Akoonu Oro agbaso naa ni a mo si afo agbaran. Oro agbaso:- je siso oro ti a gbo lenu oloro fun elomiran. Iru oro tabi iroyin bee gbodo je eyi to ti koja. Oro agbaso le

IBA ISELE ORÍKÌ ORÍṢI IBA ÌṢẸ̀LẸ̀

Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 4 OSE KERIN IBA-ISELE – Oriki – Orisii iba-isele – Awon wunren ti o toka iba-isele Akonu: ORI-ORO:  ASIKO ATI IBA ISELE ORIKI EYA IBA ISELE AKOONU Asiko je oro girama ti a maa n lo lati fi toka si asiko ti isele kan

DIDA ORO ORUKO TI A SEDA MO YATO SI EYI TI A KO SEDA

SUBJECT: YORUBA CLASS: SS 3 TERM: FIRST TERM OSE KETA DIDA ORO ORUKO TI A SEDA MO YATO SI EYI TI A KO SEDA Ori-oro-: Dida oro – oruko ti a seda mo ninu gbolohun Isunki ati aranmo ninu awon oro–oruko ti a seda Akoonu Bi a se le da oro – oruko ti a

ISORI GBOLOHUN

SUBJECT: YORUBA CLASS: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: SECOND WEEK  OSE KEJI ISORI GBOLOHUN Oríkì Ìsorí gbólóhùn pèlú àpẹẹrẹ Akóónú Gbólóhùn ni ìpèdè tí ó kún, tí o sí ní ìse tí ó ń jé. Gbólóhùn jé ìsọ tí ó ní ìtumo kíkún. A fún àwon gbólóhùn Yorùbá ní orúkọ gégé bí íse tí

OSE KIN-IN-NI ORO – ISE

SUBJECT: YORUBA CLASS: SS 3 TERM: FIRST TERM ORO – ISE     OSE KIN-IN-NI ORO – ISE Oro – ise ni oro tabi akojopo oro ti o n toka si isele tabi nnkan ti Oluwa se ninu gbolohun. Oro–ise je opomulero fun gbolohun laisi oro–ise ninu gbolohun ko le ni itumo.     Apeere