YORÙBÁ PRIMARY 4 Ọ̀sẹ̀ Kínní (Week 1) – 11/9/2024 AKÓLÉ-ÈDÈ: Òǹkà Nínú Èdè Yorùbá Àwọn Ọ̀rọ̀ Òǹkà: Ọgọ́rùn-ún: 100 Àádọ́ta: 50 Àárùndínnígọ́ta: 55 (Àádọ́ta Dín Inú Mẹ́wàá) Àárùn-ún: 5 Ọ̀gọ̀rùn-ún Dín Inú Mẹ́wàá: 95 Ọ̀gọ̀rùn-ún Mẹ́wàá: 60 Òǹkà Nínú Àwọn Ìṣírò: 10 x 2 = 20 20 x 3 = 60 20 x 4 =
Edu Delight Tutors LAGOS 1st TERM EXAMINATION CLASS: Basic 5 SUBJECT: Yoruba SECTION A: Objective Questions Ole jija je iwa omoluabi a. Bẹni b. Bẹẹkọ ____________ ni oruko oye oba ilu Oyo a. Aalafin b. Orangun c. Oba Awon agbe ma n ran arawon lowo nipa aaro sise a. Bẹni b. Bẹẹkọ Ole jija iwa
Class: Pry five Subject: Yoruba Studies Akole: akanlo ede ati itunmo re Se aya gbangba! Itumo: ki eniyan doju ko isoro lai beru Ya apa! Itumo: ki eniyan ma itoju owo tabi ohun ti a fi owo ra Edun arinle! Itumo: eni ti o ti loeori sugbon ti opa da rago
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… AYEWO Iru leta wo ni a nko sile ile-ise ? (a) leta aigbefe (b) leta gbefe (d) leta onibeji Ewo ni o je mo ere idaraya ninu awon wonyii: (a) ijala (b) sango pipe (d) bojuboju Pari owe yii: Eni ti yoo
THIRD TERM SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KARUN-UN Dahun gbogbo awon ibeere wonyi Aroko alariyanjiyan maa n da lori ______ (a) ise sise (b) iyan jija (d) ija jija Apeere oro oruko alaiseeka ni____(a) iyo (b)
…………………………………………………………………………………… Ko orin ibile kan fun ayeye, eyikeyi ti o ba mo, o le je nibi igbeyawo, nibi isomo loruko tabi nibi oye jije Daruko igbese marun-un ninu asa igbeyawo abinibi ki o se alaye okan ninu won IWE KIKA DAROSA Kini so darosa di olokiki? (a) ile ti o
AWON OWE ILE YORUBA NIPA ILAANA ALIFABEETI ÈDÈ YORÙBÁ Òwe leshin ọ̀rọ̀, ọrọ leshin òwe, tí oro bàa sọnù, owe laa má ń fii wàá ( ABD NI PIPA OWE) A =Aigbofa lanwoke, ifa kan kosi ni para B = Bami na omo mi, ko denu Olomo D = Didun lodun labore jeko tile
SECOND TERM EXAMINATION 2019 CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… 1.) Ko orin ibile kan fun ayeye, eyikeyi ti o ba mo, o le je nibi igbeyawo, nibi isomo loruko tabi nibi oye jije 2.) Daruko igbese marun-un ninu asa igbeyawo abinibi ki o se alaye okan ninu won IWE KIKA DAROSA
Pry five Akole:SILEBU KINI A NPE NI SILEBU Silebu ni fonran oro ri emile gbejade lekan soso tabi silebu ni ige oro si wewe tabi silebu ni ihun ti a fi nse afaoe iro ni a mo si silebu. Ami oh un no a fi in oro si silebi,iyeami ti o ba wa lori