Yoruba

3RD TERM EXAM QUESTIONS PRIMARY 6 YORUBA LANGUAGE

      THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION  CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………… AYEWO Kiini oruko oye Oba Ile-Ife (a) Ooni (b) Alaafin  (d) Awujale  Kiini oruko oye Oba ilu Oyo (a) Alaafin  (b) Ooni   (d) Soun   Kiini itumo akanlo ede yii: Te oju aje mole (a) Ja-ole    (b) Ya-apa (d) salo 

Third Term Examinations Primary 6 Yoruba

THIRD TERM SUBJECT: YORUBA                                          CLASS: KILAASI  KEFA Dahun  gbogbo  awon  ibeere  wonyi Itumi  aropo  lede  geesi ni ____(a)  subtraction  (b)  division  (d)  addition ____ni apeere  oge sise  laarin  awon  okunrin  ni aye atijo  (a)  irun 

Yoruba Primary 6 First Term Examinations

FIRST TERM EXAMINATION 2021/2022 CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE   NAME:…   IWE KIKA: IYI ISE SISE 1. Ibo ni orisun gbogbo iwa ibaje? (a) Ile-eko (b) inu oko (d) Odede 2. Ewo ni kii se iwa ibaje ninu awon wonyii (a) ole (b) akikanju (d) ojukokoro 3. Iwa Agbeke di awokose fun awon

Ìtàn isedale Yoruba

Subject ; Yoruba Class : Basic 6 Term : Third Term Week :Week 10 Previous Knowledge : Learners have previous knowledge of how the Yoruba migrated from Meca to ILE Ifè Behavioural Objectives b By the end of the lessons, learners will be able to Say the founder of yorùbá land Explain how the Yoruba

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 6 FIRST TERM EXAMINATION 

FIRST TERM EXAMINATION  CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Iwe Kika:- Ewi Omoluabi Ninu ewi omoluabi, a rip e, omoluabi maa n _____ (a) si wahu (b) so yaya Ewi yii ko nipe, omoluabi a maa ______ (a) jeun ni won-tonwon si (b) sepe Omo ti yoo je asa mu tumo si _____ (a)

GBOLOHUN

Pry six Akole:GBOLOHUN   KINI A NPE NI GBOLOHUN?Gbolohun ni akojopo oro ti eemile gbe jade lekan soso tabi gbolohun ni ipe de ti okun ti o si ni itunmo. Orisirisi gbolohun ni o wa ninu ede yoruba lara won ni awon wonyii. 1.gbolohun ibeere 2.gbolohun alaye 3.gbolohun ase 4.gbolohun onibo 5.gbolohun alakanpo.   GBOLOHUN

Alo Apamọ́

Akole:alo apamo 1. Alo o aalo, ikoko rugudu feyin tigbo Kinni: IGBIN 2. Alo o aalo, ile gbajumo kik imi eran Kinni: IBEPE 3. Alo o aalo, iyara kotopo kiki egun Kinni:ENU 4.Alo o aalo, opo baba alo kan lailai opo baba alo lailai ojo to ba de fila pupa ni iku de ba Kinni: