ÀWỌN FAWELI ATI KONSONANTI EDE YORUBA 

 

Class: Pry one

Subject: Yoruba Studies

Akole: FAWELI ATI KONSONANTI EDE YORUBA

 

Faweli yoruba pin si ona meji awon naa nii

1 Airanmupe

2 Aranmupe

 

1 FAWELI AIRANMUPE: A E E I O O U

 

2 FAWELI ARANMUPE: AN EN IN ON UN

 

KONSONANTI

b d f g gb h j k l m n p r s s t w y

 

 

Ise kilaasi

 

1 melo ni faweli airanmupe je (a) meje (b) meta

 

2 faweli aranmupe ede yoruba je ____ (a) mesan (b)marun

 

3 konsonanti ede yoruba je _____(a)mejidinlogun (b)mejila

3 Comments

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *