ILANA ISE FUN SAA KETA OLODUN KIN-IN-NI (JSSONE) OSE KIN-IN-NI: ATUNYEWO ISE SAA KEJI OSE KEJI: EDE: LETA KIKO ASA: AWON ISE ISEMBAYE ILE YORUBA OSE KETA: LITIRESO: ASAYAN IWE TI IJOBA YAN ASA: ISE AGBE OSE KERIN: EDE: ISE ORO ISE NINU GBOLOHUN ASA: ISE ILU LILU OSE KARUN-UN: EDE: IHUN GBOLOHUN ABODE
Weekly Lesson Notes Yoruba JSS 1 First Term AKOLE ISE – ALIFABETI YORUBA Ami Ohun lori awon faweli ati oro onisilebu kan. Ami Ohun lori oro onisilebu meji SILEBU NINU EDE YORUBA Akoto ede yoruba ode-oni ONKA YORUBA LATI OOKAN DE AADOTA (1-50). OONKALELAADOTA DE OGORUN-UN (51-100). ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU
OSE KOKANLA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si. Isori oro Yoruba oro-oruko (NOUN) oro-aropo oruko (PRONOUN) oro ise (VERB) oro Aropo afarajoruko (PROMINAL ) oro apejuwe ( ADJECTIVE ) oro atoku (PREPOSITION) oro asopo ( CONJUCTION )
OSE KEWAA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AROKO ATONISONA ALAPEJUWE. Aroko je ohun ti a ro ti a sise akosile. Aroko alapejuwe ni aroko ti o man sapejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to n sele gege bi a se rii gan-an. Apeere: Oja ilu mi Egbon mi Ile-iwe mi Ouje ti mo feran Ilu mi
OSE KESA-AN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE. Aroko je ohun ti a ro ti a si se akosile re lori pepa ILANA FUN KIKO AROKO yiyan Ori-oro: A ni lati fa ila teere si abe ori-oro ti a n ko aroko le lori sise ilapa ero: A
OSE KEJO EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ONKA – OOKALELAADOTA DE OGORUN-UN (51-100). 51 Ookan le laadota 50+1=51 52 Eeji le laadota 50+2=52 53 Eeta le laadota 50+3=53 54 Eerin le laadota 50+4=54 55 Aarun din logota 60-5=55 56 Eerin din logota 60-4=56 57 Eeta din logota 60-3=57 58 Eeji din logota 60-2=58 59 Ookan
OSE KEJE EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ONKA YORUBA LATI OOKAN DE AADOTA (1-50). Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Nonba 1 Ookan 2 Eeji 3 Eeta 4 Eerin 5 Aarun-un 6 Eefa 7 Eeje 8 Eejo
OSE KEFA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKOTO AWON ORO TI A SUNKI Akotoni sipeli titun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati maa lo. Sipeli atijo Sipelu titun Olopa Olopaa Na Naa Orun Oorun Ogun Oogun Anu Aanu Papa Paapaa Suru Suusu Alafia Alaafia Oloto
OSE KARUN-UN EKA ISEl LITIRESO AKOLE ISE: Akoto ode-oni Akoto ni ona ti a n gba ko ede Yoruba ni ona ti o bojumu ju ti ateyinwa lo. Alaye lori akoto ode-oni Ede Yoruba di kiko sile ni odun 1842 Pelu iranlowo awon ajihinrere ijo siemesi bisobu Samueli Ajayi crowther ati Henry Townsend. Ile ijosin
OSE KERIN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: SILEBU Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso lai si idiwo. Iye ami ohun ti o jeyo ninu oro kan ni iye silebu iru oro bee. Ihun oro orusilebu kan le je, I faweli nikan –(F) ii Apapo konsonati ati