Akole: iwe kika Darosa
Class: Pry five
Akole: iwe kika Darosa
Ki akekoo tun iwe yii ka ni owo won nile,kiwon si dahun awon ibeere wonyii Lori re
Ki won si oju iwe ketaleladorin(73) eko kerindinlogun(16)ninu iwe kika EKO EDE YORUBA ODE ONI.
Ibeere
1.kini o so darosa di olokiki (a)ile ti oko (b)egbe ti o nko (d)eko tio ko (e)owo tio ni
2.ona wo ni darosa ngba ran mekunu lowo.(a)o nya won lowo (b)o nran wo nile eko (d) o nfun won ni ise se (e)o nya won nile gbe
3.Darosa nfe ki omode____(a)feran obi (b)maasa nile eko (d)fi oju si eko re (e)di folefole