Akanlo ede ati itunmo rẹ

 

Class: Pry five

Subject: Yoruba Studies

Akole: akanlo ede ati itunmo re

 

  1. Se aya gbangba!

Itumo: ki eniyan doju ko isoro lai beru

 

  1. Ya apa!

Itumo: ki eniyan ma itoju owo tabi ohun ti a fi owo ra

 

  1. Edun arinle!

Itumo: eni ti o ti loeori sugbon ti opa da rago

 

  1. Fi aake kori!

Itumo: ki eniyan ko jale lati se nkan

 

  1. Fi aga gbaga!

Itumo:dije, ki eniyan koju ara won lati dan agbara won woo

 

 

1. Kan ojú abé niko

Ìtùmò : kí a ṣòro paato síbi tí ọ̀rọ̀ wá

 

1. Epa ó gboro mọ

Itunmo : kò sii ATUNSHE rárá mọ

1. Tẹ ojú aje mọ́lẹ̀

Itunmo : yà apá. Kii ènìyàn má mọ itoju owó

1. Tẹti leko

Itunmo : kí a tẹti lélẹ̀ láti gbọ̀ ọ̀rọ̀ ìkòkò tàbí ìkéde pàtàkì

1. Fi iga Gbaga

Itunmo : idije tàbí ère idije

Ise kilaasi

So itumo awon akanlo ede wonyii

 

  1. Se aya gbangba

 

  1. Edu arinle

 

  1. Fi aga gbaga

 

  1. Ya apa

 

  1. Fi aake kori

 

Akanlo ede ni ile Yoruba

 

 

YORÙBÁ PRIMARY 3 FIRST TERM EXAMINATION

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share