Akole:OWE ILE YORUBA

 

Class: Pry five

Subject: Yoruba Studies

Akole:OWE ILE YORUBA

 

  1. Aso koba omoye mo, omoye ti rin ihoho woja

 

2.Bi okete ba dagba,omu omo re ni yoo mu

 

  1. Ati gbe iyawo kotejo,owo obe lo soro

 

4.ile ti afi to mo,iri ni yoo

wo

 

5.kekere lati npeka iroko,toba dagba tan apa kin kaa mo

 

6.Operekete ndagba,inu adamo nbaje adi baba tan inu bi won

 

  1. Gele o dun bi ka mo we, kamowe ko dabi koyeni,koyeni kodabi kamolo

 

  1. Omo ti yoo je asamu,kekere lo ti nsenu samusamu

 

  1. Aja ti yoo sonu,kin gbo feere olode

 

10.Eni ti yoo je oyin inu apata,kin wenu aake

 

Ise kilaasi

Pari awon owe wonyii

 

  1. Aso oba omoye mo,____(a)omoye ti sare wo oja (b)omoye ti rin ihoho wo ojoa

 

2.Aja ti yoo sonu,___(a)a rin jinna (b)kin ngbo feere olode

 

  1. Bi okete ba dagba,___(a)omu omo re ni yoo mu (b)omu baba re ni yoo mu

 

  1. Ile ti aba fi to omo,____(a) ategun loma gbe (b) iri ni yoo wo

 

5.Ati gbe iyawo ko tejo,___(a) owo obe lo soro (b) owo aso lo soro

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *