SECOND TERM EXAMINATION PRIMARY 5 YORUBA LANGUAGE

……………………………………………………………………………………

 

  1.    Ko orin ibile kan fun ayeye, eyikeyi ti o ba mo, o le je nibi igbeyawo, nibi isomo loruko tabi nibi oye jije  
  2.   Daruko igbese marun-un ninu asa igbeyawo abinibi ki o se alaye okan ninu won

IWE KIKA DAROSA

 

  1.    Kini so darosa di olokiki? (a) ile ti o ko    (b) egbe ti o nko   (d) eko ti o ko (e) owo ti o ni
  2.    Ona wo ni darosa ngba ran mekunnu lowo (a) o nya won lowo     (b) o nran won nile eko   (d) o nfun won ni ise se (e) o nya won nile gbe  
  3.   Iru iranlowo wo ni darosa nse fun awon akekoo?  (a) o nraso ile-eko fun won      (b) o nfun won ni eko-ofe    (d) o nra aso odun funwon  (e) o nfun won ni ebun owo  
  4.    Nibo ni darosa ti nri owo tire? (a) nibi ole jija    (b) nibi jibiti lilu    (d) nibi iranlowo (e) nibi ile-ise re
  5.    Darosa nfe ki omode ______ (a) feran obi    (b) maa sa ni ile-eko  (d) fi oju si eko re  (e) di fole fole  

OWE ILE YORUBA  

 

 Pari owe yii:

  1. Agba kii nwa loja __________________________________________________
  2.    Bami na omo mi, _____________________________________________________________
  3.    Ile ti a fi ito mo ______________________________________________________________
  4.  Esin iwaju, __________________________________________________________________ 5.)   Obe ti baale ile kii nje, _________________________________________________________
     
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *