Orin ibile to je mo ayeye.

Date: Friday, 1st May, 2020.

Class: Pry five

Subject: Yoruba Studies

 

Akole: Orin ibile to je mo ayeye.

 

1.) Orin I bile to je mo ayeye igbeyawo:

(a) iya mo mi lo,sadura fun mio oo

Iya mo mi lo,sadura fun mio oo

Ki maa mosi,kima kagbako nile oko

KO maa mosi,kima kagbako nile oko

Iya mo milo,sadura fun mi oo

 

(b) iyawo elese osun,aya wa nio

Iyawo elese osun aya wanio

E o raya wa bi?

E o raya wa bi?

Eyin te saya yin jati jati

E o raya wa bi.

 

2.) Orin I bile to je mo aye ye ikomojade:

(a) kuluubu yeye, oyeye kulubu

kuluubu yeye,oyeye kuluubu

a o fotun gbomojo

kuluubu yeye,oyeye kuluubu

a o fosi gbomo pon

kuluubu yeye,oyeye kuluubu

 

(b) omo lao fi gbe e e

omo lao fi gbe ×2

owo osun lowo awa

omo lao fi gbe

 

3.) Orin ibile toje mo ayeye oye jije:

(a) Borikan ba sunwo arangba oo ×2

Ori teemi sunwo,o ran wo

Borikan ba sunwo arangba

(b) oye o,oye amori baba wa ×2

baba oloye yii gbayi o gbeye

oye o,oye amori baba wa

 

Review work:

 

1.) Daruko marun-un ninu igbese igbeyawo ni aye ode oni


 

2.) Se alaye okan ninu won ni ekunrere:


Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *