Exams Questions Grade 5 Yoruba Third Term

SUBJECT: YORUBA

TIME: 1 HOUR

CLASS: GRADE FIVE

NAME OF PUPIL____________________________________

DATE __________

  1. 20 je _________ (a) ogun (b) igba (d) Eedegbeta
  2. 500 je _________ (a) Egbeta (b) Eedegbeta (d) Egberun
  3. Egberun je _________ (a)500 (b) 200 (d) 1000
  4. Igba je _________ (a) 100 (b)200 (d) 20
  5. Adie funfun ni ede oyinbo ni (a)white duck (b) black chicken (d) white chicken

Pari owe yii

  1. Adie funfun__________ (a) ologbon ni (b) ko mo ara re lagba (d) omode lo n se
  2. Ile oba to jo __________ (a) ewa lo bu si (b) ibaje poo (d) ibaje lo bu kun
  3. Bami na omo mi, ko de inu _________ (a) baba (b)iya (d) olomo
  4. Bi esin ba da ni _______ a ma n tun gun ni (a)subu (b) gule (d) gunni
  5. Ewa ni ede oyinbo je ______ (a) beautiful (b) beans (c) beauty

APA KEJI

  1. Ko owe marun ti o mo
  2. Ko awon wonyi ni ede Yoruba
    • White
    • Black
    • Beauty
    • Head
    • Cloth
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share