Ó sọnù kú sodo

Pry five

Akole:osonu ku sodo

Ninu iwe kika eko ede yoruba ki awon akekoo si eko kankandinlogun(page 19)oju ewe karundinladorun(85)ki won kaa daradara nile.ki won sii dahun awon ibeere wonyii.

 

 

Ibeere

1.iru ise wo ni osonu nse?(a)ija (b)eebu (d)eeyan nina (e)agbafo

 

2.inu osonu kii dun si (a)iro (b)nkan rere (d) ija (e)aso

 

3.tani o la oju ayaba?(a)osonu (b)oluweri (d)oba (e)emewa

 

4.oluweri toro ____lowo osonu (a)igba (b)aso (d)omi (e)odo

Sharing is Caring – Pass It On

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *