Awako Ikini-oko aree foo idahun- ogun a gbe o

Pry five

 

Ose kinni

 

 

Akole:Asa ikini ni ile yoruba

Orisirisi ona ni awa yoruba ngba ki ara wa ninu asa ikini ati lati mo omo yoruba lawujo.awon ona naa ni awon wonyi::
1 ikini ni asiko
2 ikini ni igba
3 ikini si ipo ti aba wa tabi ohun tio ba sele sii eniyan
4 ikini ni enu ise ati bi won se dahun
5 kiki oba ati ijoye gege bi ipo won
IKINI NI ASIKO
ni dede agogo meje owuro si agogo mokanla abo(11:30) ekaaro o pelu ido bale ati ikunle ni fun omokunrin ati omobinrin

Ni dede agogo mejila osan si agogo meta abo e kaasan o

Ni dede agogo merin irole si agogo mefa abo ni e ku irole o

Ni dede agogo meje ale si agogo mokanla abo e kaale o

Ni asiko ti aba fe sun o daaro ki olorun ji wa re o kamaa toju orun de iju iku oo layo ni a o ji o

2
Bi ase nki onise owo ati bi won se nda wo lohun

Alaro
Ikini- Areduo Areye o Amuabe o
idahun-olokun agbe o

Awako
Ikini-oko aree foo
idahun- ogun a gbe o

Akope
Ikini-igba aroo,emose o
idahun-amin o adupe o

Babalawo
Ikini-aboruboye o baba
idahun-aboye bo sise ifa agbe ooo

Agbe
ikini-aroko bodun deo
idahun-ami oo adupe o

Ode
Ikini-ogun afo wo jono o
Idahun- arinpa nto ogun

Onidiri
ikini- oju gbooro o
idahun oya yao iyemoja a gbe oo

Alayo
Ikini-moki ota moki ope
idahun- ota nje ope o gbodo foun

Alagbede
Ikini- Aroye o, owu aroo
idahun- ogun a gbe o

Oni sowo
Ikini-atajere o, aje awogba oo
idahun- amin adupe o

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *