ORIKI OPOMULERO 

Pry four

Akole:Asa oriki

 

Kini a npe ni oriki?Oriki je ijinle ede yoruba ti a fi nyin omo ti omo be ba se ohun to dara ki a ba le se ohun to dara miran lojo iwaju.

Asa oriki pin si ona meji ani oriki ideile bakanaa ni a ni oriki orile.

 

ORIKI IDILE

Oriki idile je oriki idile ti a ti bi omo gege bi omo yoruba bi apeere,idile onikoyi,idile opomulero abbl.

 

ORIKI ORILE

Oriki orile je oriki ilu ti a ti bi omo gege bi omo yoruba gege bi ilu eko,ilu ibadan abbl.

 

ORIKI OPOMULERO

Opomulero moje lekan

Keke ta didun aso le didi eniyan,iwanu opo omo afibi ri nyo rele wa jegbe isu.Eyin lomo opo korobi koro biti.Eyin lomo opo koro biti koro biti,opo ti ko gbonran eje ka fenue gungi.

 

ORIKI EKO

Eko adele,eko akete ile ogbon.Eko aromisa legbe legbe.Arodede maja.Okun lotun osa losi.Omi niwaju omi leyin.Omi ni ibi gbogbo.Ka jeba jeba ka je feselu.Ka mumi tupulu si.Eko niyen.Yanmu yanmu eyin igbeti nko?o le gbadie osoo ro.Obalende le yomo leti eni.Eko akete ile ogbon.Eni to deko tuo ogbon,ogbon oni toun dorun alakeji.

 

Ise kilaasi

 

1.kini a npe ni oriki?

2.ona melo ni asa orik pin si ki o se alaye ni soki.

3.so apeere kankan ninu oriki idile ati orile

(Visited 527 times, 1 visits today)
error: Content is protected !!