Yoruba Primary 4 Examination Second Term

Yoruba Primary 4 Examination Second Term

NAME:…………………………………………………………………………………… ORIKI ILU

 

 1.    Ilu wo ni a nki bayii pe, mesi ogo, nile oluyole, nibi ole gbe njare onihun (a) Ibadan   (b) Akura  (d) Oyo
 2.    Ilu wo ni a nki bayi pe, akete ile ogbon, aromisa legbe legbe (a) Egba  (b) Eko    (d) Akure
 3. )   Ilu wo ni a nki bayi pe: oloyemekun, omo a muda sile mogun enu pani (a) Akure    (b) Ilorin (d) Ondo 
 4. .)   Ilu wo ni a nki bayi pe; omo ajifi kalamu damo leko arise kandun kandun, ilu to jinna to sunmo alujona (a) Egba (b) Oyo (d) Ilorin  
 5.    Ilu wo ni a nki bayii pe, omo lisabi, oniruuru – po nile Alake (a) Ogbomoso (b) Egba (d) Ijesa  

ONKA NI EDE YORUBA

 

   Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba:

 

 1. 75 (a) arundinlogbon (b) arundinlogoji (d) arundinlogorun
 2.   Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 45 (a) arundinladota (b) arundinlogun (d) arundinlogorun
 3.  Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 90 (a) ogorun (b) adorun (d) ogota
 4. Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 110 (a) ogorin (b) ogorun (d) adofa
 5.   Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 65 (a) arundinladorin (b) arundinlogoji (d) arundinnigba  

ASO ILE YORUBA

 

 1.    Ewo ni aso ile wa ninu awon oruko wonyii (a) alari (b) akara (d) seti
 2.  Ara ti obinrin fi aso ran ni _____ ati _____ (a) gele ati ipele (b) iro ati buba (d) oyala ati dansiki
 3.  Ara to okunrin nfi aso ran ni ______ ati _____ (a) buba ati sokoto (b) iro ati gele (d) tobi ati oyala
 4. Aso ati a nran ti o ngun de orun ese ni ______ o dabi jalamia ti won ba ran tan (a) agbada (b) dandogo (d) gbariye
 5.    Aso ti o jo agbada, sugbon ko tobi to agbada ti a ba ran tan ni a npe ni _____ (a) dansiki (b) gbariye (d) oya        

 

 

  AGBON TA GBONJU

 

 1.   Kini o ta gbonju? (a) ikamudu    (b) oyin    (d) agbon          (e) kan-in-kan-in
 2.    Ninu eko yii, baba gbonju ko fe ki awon omo oun ya______ (a) ole   (b) ole    (d) olojukokoro (e) alaigboran  
 3. Itumo se imele ni ______ (a) roju      (b) gun ope     (d) ja ole    (e) ya ole
 4.    __________ ni baba gbonju (a) olowo    (b) akikanju    (d) ole     (e) okuroro
 5.   Kini koje ki baba gbonju lo si oko (a) idiwo kekere (b) ise nla   (d) oro aje   (e)  
   
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Use the search box to search for any topics or subjects that you want