SECOND TERM EXAMINATION 2019 CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

SECOND TERM EXAMINATION

CLASS: PRIMARY 2                                                        

SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

ERE AYO

 1.   ________ ni igi gbooro gidi ti a gbe iho mejila si (a) opon ayo         (b) awo ayo
 2. Omo ayo __________ ni o nwa ninu iho Kankan. (a) mejo     (b) merin
 3.   Apa ___________ ni a nta ayo si (a) otun          (b) osi
 4.   Enikan _________ ni o nta ayo olopon leekan naa (a) merin    (b) meji
 5.   Omo ayo ______ ni o ngbe ni oju opon ayo lapapo (a) mejidinladota (b) merinlelogun  

ALO  APAMO

 1.   Alo o, alo o, okun nho yaya, osa nho yaya, omo buruku tori bo, kini o (a) irin    (b) omorogun
 2.   Alo o, alo o, opa tinrin kanle, o karun, kini o (a) ojo     (b) agbara
 3.   Alo o, alo o, oruku tindin tindin, oruku tindin tindin, oruko bi igba omo, gbogbo won lo le tiro, kini o   (a) ata   (b) ewa  
 4.   Alo o, alo o, mo nlo soyo; mo koju soyo, mo nbo loyo, mo koju soyo, kini o (a) ilu     (b) igba
 5.   Alo o, alo o, aso baba mi kan laelae, aso baba mi kan laelae, eti lo ngbo, kii gbo laarin,  kini o  (a) agbara       (b) odo  

ALO APAGBE: IJAPA  ATI  OKERE  

 1.  _________ ati okere  je ore   (a) asin        (b) ijapa
 2. _______ kii  se ore won        (a) ijapa       (b) asin
 3. Ijapa la ija ___________ (a) ogbon (b) eru
 4.   Ija sele laarin ________ ati ______ (a) ijapa ati asin (b) asin ati okere
 5.  Inu bii asin gidigidi, o sig e e je ni __________ (a) imu (b) ese    

 

IMOTOTO  ILE

 

 1. _______ nge koriko ti o wa ni ayika ile (a) Tunde        (b) Kola
 2. ________ ngba idoti ati panti inu ile sita   (a) Yemi   (b) Bola
 3.  Mama ________ sese fo aso tan ni   (a) Bola      (b) Kemi
 4.    Baba ________ naa fe sun panti ti won ti ko jo nina   (a) Kola        (b) Tunde
 5.   O n sa wonsi ori _________ isasosi (a) okun      (b) igi  
SECOND TERM EXAMINATION 2019 CLASS: PRIMARY 2                             SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Use the search box to search for any topics or subjects that you want