3RD TERM EXAM QUESTIONS PRIMARY 5 YORUBA LANGUAGE

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 

CLASS: PRIMARY 5

SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

AYEWO

  • Iru leta wo ni a nko sile ile-ise ? (a) leta aigbefe   (b) leta gbefe   (d) leta onibeji
  • Ewo ni o je mo ere idaraya ninu awon wonyii: (a) ijala  (b) sango  pipe  (d) bojuboju 
  • Pari owe yii: Eni ti yoo je oyin inu apata:  (a) kii woe nu aake  (b) a fo apata ni  (d) aake a ro  ni 
  • Pari owe yii: ileti a fi ito mo: (a) Adara sini  (b) ategun a gbe lo   (d) iri ni  yoo wo
  • Kiini oruko, namba yii ni ede Yoruba 95  (a) Arundinlogoji  (b) Arundinlogota (d) Arundin logorun
  • Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba 60  (a) Ogoji  (b) Ogota  (d) Ogorun
  • _________ je okan ninu ohun ti a fin se oge ni ile Yoruba? (a) Lofinda   (b) Laali       (d) Etekikun
  • Awon ______ li ni aso osun kiko n ni ikawo  (a) Yoruba  (b) Hausa  (d) Igbo
  • Orisa wo ni a maa nyo ina lenu ________ (a) Ogun  (b) Sango  (d) Esu
  • Awon wo ni Yoruba nki bayi pe: Oju gbooroo :  (a) Alaro  (b) Awako  (d) Onidiri

ORO ISE NINU GBOLOHUN 

Ewo ni apeere oro ise ninu awon gbolohun wonyii: 

  • Olu je eba ni ale: (a) Olu (b) eba (d) Je
  • Isola pa eran ti o tobi : (a) Pa (b) Isola (d)  Eran
  • Yemi lo si ile-iwe: (a) Yemi (b) Si (d) Lo 
  • Wale mu emu ni oko: (a) Oko (b) Wale (d) Mu
  • Agbe gbin Agbada: (a) Gbin (b) Agbado (d) Agbe

 

IWE KIKA: AGBEPO LAJA  

  • Bawo ni Tayo se jesi Abiola   (a) egbon (b) ore (d) aburo 
  • Tani o ru apere   (a) Abiola (b) Egbon (d) Tayo 
  • Kini baba Olosan pinnu lati se fun Tayo ati Abiola? (a) o pinnu lati na won 

(b) o pinnu lati so fun baba won (d) O pinnu lati fun won ni osan  

  • Kini o je ki oro naa dun Abiola pupo 
  • won fi oju ole wo (b) owo ko te Tayo   (d) o je iya ona meji   
  • Ona wo ni Abiola fi je onigbowo fun Tayo 

(a) Oduro nidi igi osan   (b) O gba osan kale   (d) O ru agbon osan   

IWE KIKA: ISEGUN OYINBO 

  • Omo melo ni Iya Alabi bi ye? (a) omo kan (b) omo meta (d) omo meji 
  • Kini  mu ki Asabi ke tooto (a) Ebi npa omo re  (b) Oko re kosi nile (d) Giri mu omo re 
  • Iru egboogi wo ni won gbe wa fun omo Iya Alabi 

(a) Ebi npa omo re (b) Giri mu omo re  (d) Oko re ko si nile 

  • Nigba wo ni Alabi ti pinnu lati ko nipa isegun oyinbo 

(a) leyin iku aburo re    (b) leyin ti o jade ile iwe   mefa (d) leyin ti o pari mewa 

  • Nibo ni Alabi tin se ise isegun oyinbo (a) ni yunifasiti (b) ni abule won (d) ni ilu oyinbo 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share