1st Term Examination YORUBA JSS 2

Edu Delight Tutors

Subuode Gbaga Gasline Ogun State

1st Term Examination

YORUBA

JSS 2

IPIN A

 1. Ewo ni ki ise litireso alohun? (a) yala (b) rara (d) okoto tita
 2. Ewi awon eleegun ni (a) iyere (b) iwi (d) sango pipe
 3. Awon babalawo ni wom n sun (a) iyere (b) iwi (d) rara
 4. Bolojo je ewi eya (a) Oyo (b) egbado (d) Ondo
 5. Okan ninu anfaani litierson alohun nip e a fi n (a) sepe (b) jeun (d) danilaraya
 6. Faweli aranmupe ni (a) I (b) o (d) an
 7. Faweli roboto ni (a) an (b) e (d) o
 8. Iro consonanti ni (a) g (b) u (d) e
 9. Iro consonanti asesilebu ni (a) f (b) n (d) k
 10. Oro-ise ni o n je ka mo —– ninu gbolohun (a) abo (b) oluwa (d) koko
 11. O di dandan ki gbolohun ni ——- (a) apejnwe (b) oro-ise (d) oro-eyan
 12. Ile ti mo ko tobo, je gbolohun (a) onibo (b) ala kanpo (d) abode
 13. ‘ase jere ni temi’ je apeere gbolohun (a) ayisodi (b) oniroy ni (d) ijehen
 14. Igbese kin-in-ni ninu asa igbeyawo ni (a) iwadii (b) idana (d) ifojusode
 15. Agbodegba laarin iyawo afesona ati oko re ni (a) bab oko (b) Alarina (d) iya iyawo
 16. Orin ti iyawo n ko ki awon ebi re to ba fe lo sile oko ni (a) ekun iyawo (b) ofo (d) iyere
 17. Igbeyawo ode oni n daru nitori ko si asa —-mo (a) iwadii (b) ipalemo (d) idana
 18. Igbeyawo soosi ko fi aaye gba okunrin lati fe ju iyawo ——— lo (a) meji (b) meta (d) kan
 19. Oro ti won koko se fun iyawo lenu ona ile oko re ni (a) bibo bata re (b) wiwon omi sii loju (d) fif omi we lese
 20. Ojo wo ni Yoruba n pe ni ojo aiku (a) Monday (b) Sunday (d) Wednesday

IPIN B

DAHUN IBEERE META PERE

1. Bawo ni Yoruba se n ki awon osise won yii (a) Babalawo (b) Agbe (d) Onidiri

2. Kin ni gbolohun? (a) daruko eya gbolohun marun-un nipa ise won

3. (a) ko awon eto ati liana igbeyawo sile ni sise n tele (b) kin ni awon ohun marun ti

Yoruba n gba fun idana

4. Tun awon iro wonyi ko ni liana adako fonoloji (a) k (ii) y (iii) s (iv) o (v) E

5. Koruko amutorun wa mewa (10)