YORUBA LANGUAGE THIRD TERM PRIMARY 1 , 2 , 3, 4, 5 AND 6

EDU DELIGHT TUTORS

 

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:………………………………………………………………………………………

Imototo

 1. Fo ___________ re bi o baji (a) eyin (b) inu
 2. Ge _________ re ni asiko ti o ye (a) imu (b) irun
 3. Ge _____________ re ti ogun sobolo (a) eekanna (b) imu
 4. Gba _________ re pelu (a) ita (b) ayika
 5. Fo __________ re ki o mo toni toni (a) aso (b) inu

Alo Apamo:

 1. Alo o, alo o, ki lo bo somi, ti ko ro to, kini o (a) okinni (b) irin
 2. Alo o, alo o, kilo ba oba jeun, ti ko palemo (a) Abe (b) Esinsin
 3. Alo o, alo o, kilo koja niwaju oba ti ko ki oba, kini o (a) Agbara ojo (b) Esinesin
 4. Aloo, aloo, okun nho yaya, osa nho yaya, omoburuku tori bo (a) irin (b) omorogun
 5. Alo o, alo o, oruku tindin tindin, oruku tindin tindin, oruku bi igba omo gbogbo won lo le tiro, kini o (a) Ata (b) Ewa

ITAN KOKO IYA ARUGBO

 1. __________ kan wa ni aye atijo (a) Baba (b) Egbon
 2. O bi omokunrin ________ (a) mewa (b) meje
 3. Okan ninu won losi ____________ iya arugbo ile won je (a) koko (b) ewa
 4. _____________ beere eni ti o ji koko ounje (a) Baba arugbo (b) Iya arugbo
 5. Awon omo naa si __________ lokoolan lori afara (a) Bura (b) Korin

ITAN IJAPA ATI YAN NIBO

 1. O pe ti _______________ ko ti ri omo bi (a) yannibo (b) ijapa
 2. O wa bere si i ______________ (a) ke (b) banuje
 3. Ijapa ba to ___________ lo (a) babalawo (b) esu
 4. Babalawo se ___________________ oogun fun-un (a) iresi (b) obe
 5. Ijapa oko yannibo ____________ (a) loyun (b) bimo

 

EDU DELIGHT TUTORS

 

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:………………………………………………………………………………

Imo Toto

 1. ____________ nge koriko ti o wa ni ayika ile won (a) Tunde (b) Kola
 2. ____________ naa ngba idoti ati panti inu ile sita (a) Yemi (b) Bola
 3. O nsa won si ori ____________ isasosi (a) Okun (b) Irin
 4. _______________ Tunde ko gbeyin rara (a) Egbon (b) Aburo
 5. Bi e ba sise tan, e maa gbagbe lati ______________ (a) we (b) sun

Ipin Keta: Ikini

 1. __________ ni omo kunrin nki baba tabi iyare (a) ido bale (b) ikunle
 2. __________ ni omo binrin nki baba ati iyare bi o ba ku (a) ikunle (b) idobale
 3. E ku otutu nla ki ni nigba _____________ (a) oye (b) ojo
 4. E ku ogbele yii, e ku ooro ni a nki ni nigba ___________ (a) eerun (b) ojo
 5. Ni dede agogo mejila si agogo meta abo, a maa nki ni ni ile Yoruba pe _____

(a) kaaroo (b) e kasano

Ise Agbe

 1. __________ ni Oba (a) Agbe (b) Ode
 2. Agbe lo ngbin _________ (a) okuta (b) isu
 3. Isu ti a fi ngun ________ (a) amala (b) iyan
 4. Agbe lo nbgin __________ (a) ogede (b) Igbin
 5. Agbe lo ngbin paki, paki ti a fi nse _________ (a) elubo (b) gaari

Alagbede

 1. Talo nro oko ati ada (a) Alagbede (b) Agbe
 2. Nibo ni won ti nro (a) oko (b) agbede
 3. Kilo fi nro won (a) paanu pelebe (b) irin pelebe
 4. Kiini awon ohun elo ise alagbede (a) ewiri (b) Agba
 5. __________ ni o nlo oko ati ada ti Alagbede nse (a) ode (b) Agba

 

EDU DELIGHT TUTORS

 

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………………

ASA IKINI

 1. Iya _____________ sese bimo ni (a) Sola (b) Yemi
 2. Iya ______________ fe lo ki i (a) Adunni (b) Alake
 3. O ba ti o gbe __________________ naa lowo (a) Ikoko (b) Oyun
 4. Bawo ni a se nki eni ti o nsile (a) ile a tura o (b) ile rewa o
 5. Bawo ni a se nki eni ti o bimo (a) Eku ise omo (b) E ku ewu omo

Owe Ile Yoruba

 1. Pari owe yii: Bami na omo mi ___________________________________________________
 2. Pari owe yii: Agba kii nwa loja, _________________________________________________
 3. Pari owe yii: Ile la nwo, ________________________________________________________
 4. Pari owe yii:: Esin iwaju, _______________________________________________________
 5. Pari owe yii: Ile ti a fi ito mo, ___________________________________________________

Ipolowo Oja

 1. Oja wo ni a npolowo bayii: langbe jinna o, oroku ori ebe (a) alagbado (b) orisu
 2. Oja wo ni a npolowo bayii: gbetuuru o, omi akerese, kii ndun lodo, to ba dele, adoyin

(a) eleran (b) eleja tutu

 1. Oja wo ni a npolowo bayii: ___eleelo, o gbona feli feli, (a) asaro (b) iyan
 2. ___________ re, obe re, ewojo ob eke mu _________ (a) isu (b) iyan
 3. Oja wo ni a npolowo bayii: gbanjo, gbanjo, ko lo nle, ko dowo o, oyinbo wo gbese

(a) aso (b) ounje

ETO AGBOOLA: EBI IKEKERE

 1. Ipo wo ni baba ko ninu ebi re ____________ (a) olori (b) alagbara
 2. Opo kanni _______________ je ninu ebi re (a) egbon (b) iya
 3. Awon _________________ ni opo keta ninu eto ebi (a) omo (b) ebi
 4. Ise Iya ni lati rii pe ____________ ati ______________ gbogbo ebi nbo si asiko

(a) lilo ati dide (b) jije ati mimu

 1. Ise baba kii se “keremi”, kini itumo “keremi” (a) kekere (b) nla

3rd Term Pry 2 Exams Yoruba

 

Yoruba BASIC 2 1st TERM EXAMINATION Primary 2

 

SECOND TERM EXAMINATION 2019 CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

 

 

EDU DELIGHT TUTORS

 

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:…………………………………………………………………………………………………………………………………………………

IWE KIKA: BALOGUN IBIKUNLE

 1. Balogun Ibikunle je omo (a) Ibadan (b) Ogbomoso (d) Ijaye
 2. Ninu awon ogun ti Balogun Ibikunle ja ni ajabegun ni ogun: ______

(a) ijaye ati kutuje (b) Ibadan ati Ijaye (d) ogbomoso ati Ibadan

 1. A fi Ibikunle joye Balogun nitori pe o _______

(a) je omo ogbomoso, o si lowo (b) Jagun ajasegun pupo fun Ibadan (d) bimo, o si kole

 1. Balogun Ibikunle lokan tumo si pe o ________

(a) le farada isoro (b) ijegun pupo (d) ni okan ninu ara re

 1. Se alaiye meji ninu ebun ti ibikunle ni ti fi tayo awon elegbe re:

________________________________, _________________________________

 

IWE KIKA: EFUNROYE TINUBU

 1. Oloye Tinubu je ibatan ___________ (a) Akintoye (b) Kosoko (d) Geso
 2. Ohun ti o so Iyaafin Tinubu di olowo ni _________ (a) awon egba (b) owo sise (d) Dosunmu
 3. Awon Egba fi Iyaafin Tinubu je oye iyalode nitori _______

(a) awon eru re po (b) o lowo, olooto, o lola (d) o ran Egba lowo

 1. Iyato to wa laarin Tinubu ati Efunsetan ni pe, Tinubu __________

(a) ni opolopo eru (b) feran gbogbo eniyan (d) je akoni obinrin

 1. Owo re pelu awon oyinbo mo ki o _______ gidigidi (a) binu (b) lagbara (d) lajo

AKANLO EDE

 1. Kini itumo akanlo ede yii: Tu teru nipa:

(a) Ki eniyan ku (b) Ki eniyan salo (d) Ki eniyan bimo

 1. Kini itumo akanlo ede yii: Fi aake kori

(a) Ki a fi aake si aarin ori (b) Ki eniyan ko jale lati se nnkan (d) Ki eniyan salo

 1. Kini itumo akanlo ede yii: Edun arinle: _____ (a) Edun ti o nrin nile

(b) Edun ti o gbooro gan-an (d) Eni ti o ti lowo ri, sugbon ti o pada raago

 1. Kini itumo akanlo ede yii: E pa ko boro mo:

(a) e pa ko si ninu oro (b) ko si atunse mo (d) ko si epa mo

 1. Kini itumo akanlo ede yii: Kan oju abe niko: (a) ki a soro pato si ibi ti oro wa

(b) ki a kan abe ni iko (d) Ki a maa kana be daadaa

AWON OWE ILE YORUBA

 1. Pari owe yii: Ile ti a fi ito mo, ___________________________________________________
 2. Pari owe yii: Kekere lati npeka iroko _____________________________________________
 3. Pari owe yii: Aja ti yoo sonu, ___________________________________________________
 4. Pari owe yii: Agba kii nwa loja, _________________________________________________
 5. Pari owe yii:: Eni jin si koto, ____________________________________________________

 

EDU DELIGHT TUTORS

 

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………………

 1. Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, January _______________ (a) Seere (b) Erena
 2. Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, February _______________ (a) Igbe (b) Erele
 3. Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, March _________________ (a) Erena (b) Igbe
 4. Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, April ___________________(a) Ebibi (b) Igbe
 5. Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, May ____________________(a) Belu (b) Ebibi

ORO ISE NINU GBOLOHUN

Fa ila si eyi ti o nse oro ise ninu awon gbolohun wonyii:

 1. Wale je eba ni ale
 2. Isola pa eran ti o tobi
 3. Yemi ra iru ati iyo ni oja
 4. Tunde mu emu ni oko baba Sule
 5. Yetunde sun si ori ibusun re

IWE KIKA: AGBEPO LAJA

 1. Bawo ni Tayo se jesi Abiola (a) egbon (b) ore (d) aburo
 2. Tani o ru apere (a) Abiola (b) Egbon (d) Tayo
 3. Kini baba Olosan pinnu lati se fun Tayo ati Abiola? (a) o pinnu lati na won

(b) o pinnu lati so fun baba won (d) O pinnu lati fun won ni osan

 1. Kini o je ki oro naa dun Abiola pupo

(a) o je iya ona meji (b) owo ko te Tayo (d) Baba gba osan re kale

 1. Ona wo ni Abiola fi je onigbowo fun Tayo

(a) Oduro nidi igi osan (b) O ru agbon osan (d) O gba osan kale

IWE KIKA: ISEGUN OYINBO

 1. Omo melo ni Iya Alabi bi ye? (a) omo meta (b) omo kan (d) omo meji
 2. Kini mu ki Asabi ke tooto (a) Ebi npa omo re (b) Oko re kosi nile (d) Giri mu omo re
 3. Iru egboogi wo ni won gbe wa fun omo Iya Alabi

(a) Egboogi Ibile (b) Egboogi oyinbo (d) Egboogi to pe nile

 1. Nigba wo ni Alabi ti pinnu lati ko nipa isegun oyinbo

(a) leyin ti o jade ile iwe (b) leyin iku aburo re (d) leyin ti o pari eko re ni yunifasiti

 1. Nibo ni Alabi tin se ise isegun oyinbo (a) ni abule (b) ni ilu oyinbo (d) ni yunifasiti

 

ISLAND BUILDERS BAPTIST SCHOOL

(NURSERY & PRIMARY)

15, TAPA STREET, OFF FREEMAN, LAGOS.

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

ORUKO OYE OBA ALAYE

 1. Kiini oruko oye Oba Oyo (a) Alaafin (b) Oloyo (d) Lamidi
 2. Kiini oruko oye Oba Ile-Ife (a) Onife (b) Ooni (d) Enitan
 3. Kiini oruko oye Oba Ilu Egba (a) Olowo (b) Elegba (d) Alake
 4. Kiini oruko oye Oba Ilu Ijebu Ode (a) Awujale (b) Onijebu (d) Sikiru
 5. Kiini oruko oye Oba Ilu Osogbo (a) Soun (b) Ata Oja (d) Okere

Akanlo Ede

 1. Kiini itumo akanlo ede yii: Fa omo yo

(a) Ki eniyan mu omo jade (b) Ki a se ase yori (d) Ki a ni omo pupo

 1. Kiini itumo akanlo ede yii: Eja nba kan

(a) Iroyin buburu tabi, iroyin rere (b) Eja ati akan ni nejeeji (d) Eja kan, Akan kan

 1. Kiini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo

(a) Epa ko si ninu oro (b) Ko si atunse mo (d) Epa ko le ba oro

 1. Kiini itumo akanlo ede yii: Edun arinle (a) Edun ti o nrin ni ile

(b) Edun ti o po ganan (d) Eni ti o ti lowo ri sugbon ti o pada raago

 1. Kiini itumo akanlo ede yii: je oju ni gbese

(a) Dara lati wo (b) san gbese fun oju (d) Oju gbese to dara

IWE KIKA: AJALA TA N NA O

 1. Kiini awon ara abule sefun Ajala (a) won buu (b) won kii (d) won na an
 2. Ajala maa nse ___________ kiri abule (a) agidi (b) ijangbon (d) omoluabi
 3. Omo ________________ ni Ajala (a) lile (b) oponu (d) ole
 4. Tan ni suur tumo si __________________

(a) mu suuru patapata (b) iluwa to le mu ni binu gan-an (d) gba suuru tan

 1. Itumo fa ijangbon ni __________ (a) da wahala sile (b) mu ijangbon dani (d) ni ijangbon lawo

IGBAGBO ATI ERO YORUBA NIPA OLODUMARE

 1. Tan Olodumare?
 2. So meji nipa Igbagbo awa Yoruba nipa Olodumare