ÀWỌN ONÍRÚURÚ OWE ILE YORUBA

.

Class: Pry two

Subject: Yoruba Studies

Akole:OWE ILE YORUBA

 

1 Bami na omo mi,ko de inu olomo

 

2 Agba kin wa loja, ko ri omo tuntun wo.

 

3 Esin iwaju ni teyin wo sare.

 

4 ile la nwo,kato somoloruko

 

5 Obe ti baale ile kin nje,iyale ile kii nse.

 

 

Ise kilaasi

Pari awon owe wonyii

 

1 Bami na omo mi,_______(a)kode inu olomo (b) owo dun iya e ni

 

2 Agba kin wa loja,______(a)kinu o bini (b)kori omo tuntun wo

 

3 Esin iwaju ______(a) ni teyin wo sare (b) lo gbe ipo kinni

 

4 Ile la nwo,_____(a)kato sise (b) kato somoloruko

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *