DAUDA JALE AGBON

*NAME:……………………………………………………………………………………*

*IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON *

1.)   Omo melo ni baba Dauda bi? (a) meji            (b) meta         (d)
okan         (e) merin

2.)   Kini ise awon omo wonyii (a) agbe     (b) ode          (d) ademu
(e) akekoo

3.)   Eranko wo ni a kii je, ti Dauda maa npa (a) Eye       (b)
Emo          (d) Adan    (e) Alangba

4.)   Kini o mu ki won re roba Dauda? (a) o fin pa eye                (b) o
fin pa adan

(d) koje ki o koju si eko re       (e) o fi fo agbe emu

5.)   Kini Dauda fi ile agbon pe? (a) ile-eye          (b) ile-eku     (d)
adan         (e) agbe-emu

*IWE KIKA: – LAMURIN YA WERE *

1.)   Iru eniyan wo ni baba Lamurin (a) oba          (b) olowo      (d)
talaka       (e) ode

2.)   Ojo wo ni isele yii waye ganan (a) ojo ose    (b) ojo odun  (d) ojo
oja     (e) ojo ere

3.)   Kini Lamurin lose ni oko ni ojo naa

(a) o lo wa igi      (b) o lo he ekuro       (d) o lo sa obi            (e)
o lo wa isu

4.)   Kini o mu inu bi Lamurin

(a) ko gbadun iwe naa   (b) o ri ewu re lorun elomiran  (d) omi odo ko kaa
lara  (e) orun wo o

5.)   Kini awon ero oja fi na lamurin (a) ada          (b) kumo        (d)
opa           (e) owo

*IWE KIKA: – WARA*

1.)   Awon wo lo nse wara (a) maluu (b) Fulani (d) bomubomu (e) kolobo

2.)   Ni akoko wo ni won maa nbere ise wara sise (a) osan (b) iyale ta (d)
owuro (e) oyanjo

3.)   Ara eranko wo ni won ti nri wara (a) agbo (b) opije (d) ako maluu (e)
abo maluu

4.)   Iru ewe wo ni won fin se wara (a) ewe ope (b) ewe odan (d) ewe ibepe
(e) ewe bomubomu

5.)   Ounje miran ti a maa nsebi wara ni _____ (a) isu (b) eko (d) oka (e)
eba

*IKINI LENU ISE ATI IDAHUN*

S/N

Onise

Ikini

Idahun

1.)

Alagbede

2.)

Akope

3.)

Babalawo

4.)

Alaro

5.)

Onidiri

6.)

Awako

7.)

Onisowo

8.)

Alayo

9.)

Ode

10.)

Amokoko

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share