SECOND TERM EXAM BASIC 4 YORUBA

Edu Delight Tutors

LAGOS

SECOND TERM EXAM

BASIC 4

1. Ewo ni ki se elo idana ni ile yoruba

(a) Epo pupo (b) isu (c) ewa

2. Oko ati iyawo maa n wo aso __________ ninu igbeyawo

(a) Igbalode (b) ibile (c) idoti

3. Ewo ni kii nse orisi owe ni ile Yoruba?

(a) Owe alaye (b) Owe ipaniyan

4. ___________ no olori ilu ni ile yoruba.

(a) Obi (b) Emir (c) Oba

5. _____ kin se oye ni ile yoruba

(a) Mallam (b) Balogun (c) Lisa

6. Igba keji Oba ni agbegbe ni anpe ni _________-

(a) Ore Oba (b) Iyawo Oba (c) Otunba

7. ___________ je ounje ni agbegbe Ijebu – Ode

(a) Ore Oba (b) Ikokore (c) Iyan

8. _____________ ti ilu Ibadan

(a) Alafin (b) Olubadan (c) Ooni

9. ____________ ti ilu Ife

(a) Alake (b) Alafin (c)Oni

10. OLoye Obirin ma n je ___________

(a) Oba (b) Iyalode (c) Balogun

APA KEJI

(1) Daruko awon ohun idana meta ni ile yoruba

(2) Daruko awon oloye meta ti o mo.

(3) Bawi ni ase pe awon Oba Ilu yoruba wonyi

Apeere ota – olota ti ota

ῐǀư ọrưkỏ Oba

Ԑgbặ

ῖbặdặn

ifẻ

ờyờ