Alo apamọ́ àti àwọn ìdáhùn wọn

 

Class: Pry four

Subject: Yoruba Studies

Akole: Alo apamo

 

  1. Alo o aalo, ikoko rugudu feyin tigbo

Kinni: IGBIN

 

  1. Alo o aalo, ile gbajumo kik imi eran

Kinni: IBEPE

 

  1. Alo o aalo, iyara kotopo kiki egun

Kinni:ENU

 

4.Alo o aalo, opo baba alo kan lailai opo baba alo lailai ojo to ba de fila pupa ni iku de ba

Kinni: ABELA

 

  1. Alo o aalo, kilo koja niwaju oba ti ko ki aba

Kinni: AGBARA OJO

 

Ise kilaasi

 

  1. Alo o aalo, ikoko rugudu feyin tigbo kinni o

(a). Igbin. (b) Isawuru

 

  1. Alo o aalo, ile gbajumo kiki imi eran kinni o

(a) Agbalumo (b) Ibepe

 

  1. Alo o aalo, iyara kotopo kiki egun kinni o

(a) Enu. (b). Eyin

 

  1. Alo o aalo, opo baba alo kan lailai opo baba alo kan lailai ojo to ba de fila pupa ni iku de ba kinnio

(a) opo ina. (b) Abela

 

  1. Alo o aalo, kilo koja niwaju oba ti ko ki oba kinni o

(a) Agbara ojo. (b) Esinsin

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share