SECOND TERM EXAMINATION  CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

 

 

SECOND TERM EXAMINATION 

CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:………………………………………………………………………………

Ojo ojumo ni Ade n fo eyin re

Bo ba fo o tan

A we gbogbo ara re da saka

Nitori eeri ara

Ade ki i rinrin idoti

Eekanna re a mo tonitoni

Aso re a mo nini ni gbogbo igba

Ma a gbeyin rira laaye

Arun ti gbabe eekanna ko kere

Ki aisan ma ba gbe o de

Ibeere

  1. ______________ ni Ade n fo eyin re (a) ose kan (b) ojojumo (c) osu meji
  2. Ade ki i rinrin ___________ (a) mimo (b) janduku (c) idoti
  3. Arun ti nbe labe __________ ko kere (a) eekanna (b) irun (c) abia
  4. A gbodo ma we ara ko ___________ (a) ma a yo (b) da saka (c) ma bo
  5. Ti a ba we dada, __________ o ni gbe wa de (a) erepa (b) orun (c) aisan
  6. Ni ile Yoruba, Agbada je aso _________ (a) okunrin (b) obinrin (c) eranko
  7. Gele je aso ____________ (a) isere (b) imurode (c) ise
  8. Osu _________ ni osu ope (a) kejila (b) kini (c) kefa
  9. Orisirisi aso ni Yoruba ma n wo ki oyinbo to de (a) Beeni (b) Beeko
  10. __________ je ounje ile Yoruba (a) sharwama (b) chicken and chips (c) amala

Theory:

Dahun gbogbo ibeere wonyii

Ko onka ni ede Yoruba (1 – 10)

1  =

2 =

3 =

4 =

5 =

6 =

7 =

8 =

9 =

10 =

Ko awon ojo wonyi ni ede yoruba 

Sunday _______________________

Monday _______________________

Tuesday _______________________

Wednesday ______________________

Thursday _______________________

Friday _______________________

Saturday _______________________

Daruko osu marun ni ile Yoruba ati oruko geesi won

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share
Use the search box to search for any topics or subjects that you want