Yoruba Language Jss 1 First Term Examinations
CLASS:
TIME:
NAME
OBJECTIVES
Ka ayoka isale yìí ko si dahun an awon ibeere ti o tele;
Ninu ile kọọkan ni ile Yoruba, o je asa pe ki baba ati iya maa ko awon omo won ni eko iwa hihu
Lati kékeré ni iru eko yii ti n bere, Bi omode ba ji ni owuro, o ni liti mp bi a ti’n ni láti ki lya ati baba re awon miiran ti o dagba ju u jp pelu nind ilé naa. E ku aaro sa tabi “Ejire ma”, ko si dobale fun won daradara bi o je okunrin tabi ki o kunle bi o ba je obinrin. Awon obi ni Jati ko gmo won pelu lat boju ati lati run orin ki won to’ jeun ni aaro ati lati we ki won si mu aso ti o dara si ara. Ninu ile onigbagbo tabl imole, qmode ni lati mo bi a ti I gbadura ni òwúrò ati ní alẹ
ale.
1. Eko-ile je mo
a) iwa híhu
b. Arun sise
C. Igboya
d Awilgho
2. Bi omode ba ji ohun akoko ni lati
awon obi re
a. Bu
b. Ki
C. Na
d. Fa
3. Iwonyi ni omqde gbodo se láaró, afi o
gbodo
4. Ki obi re Run onn
b.
C. Gbadora d. Rerin-in
Qmokunrin gbodo. ki obí re fauro
Kunle
b. Naro
Dobale
d. Losoo
5. Omode ni lati ran obi re lowo lati
ayali
a. Gba ile
b. Fo awo
C. Sun
d. Fo aso kekeke
6. Leta ti bere alifabeeti ede Yoruba ni
a. B
b. D
C. A
D. F
7. Leta yìí ló parí alifabeeti èdè Yorùbá
a. A
b. B
C. Y
D. T
8. Alifabeeti ede Yoruba je
a. 24
b. 25
C. 26
d. 27
9. Baba Oduduwa ni
a. Buraimo
b. Lamurudu
C. Okanbi
d. Agbonniregun
10. Esin akoko ti won n sin
a. Kirisiteni
b. Musulumi
C. Beula
d. Iborisa
11. ___ ni olori awon eniyan ti Oduduwa ba ni ile-ife
a. Eji-ogbe
b. Agbonniregun
c. Oranmiyan
d. Moremi
12.. ____ ni o mu Orunmila binu goke lo sì orun
a. Alara
b. Olowo
C. Ajero
d. Elejelu-ope
13. ___ ni ojo tó Odùduwà ati awon omo rèé fín rìn láti meka de ile ife
a. Aadorun un
B. Ogorun un
C. Àádọ́jọ
D. Ogorin
14. Gbólóhùn tí a kòtò rẹ kò tán náà ni __
a. Se o ti jeun
B. Bola ti lo
C. Akekoo rewa
d. Mo lo si offa
15. “Onje na yo mi” ni a ko ba yìí
a. Ounje na yo mi
b. Ounje na ayo mi
C. Onje naa yomi
d. Ounje naa yo mi
15. Oro ti akoto re dara ni
a. Eniyin
b. Shagam
C. Kekoo
d. Offa
16. Iwe meji ati iwe kan je iwe
a. Meji
b. Meta
c. Merin
d. Marun-un
17. Aadota ni onka yoruba ni
a. 30
b. 40
c. 50
d. 60
18. Ti a bar o 99 mo 1, a je
a. Ogbon
B. Ogun
c. Ogójì
d. Ogorun-un
19. 20+20 ni onka Yoruba je
a. Ogun
b. Ogbon
c. Ogoji
d. Aadota
20. Iwa ati isese awon eniyan kan ni apapo ni
a.Asa
b. Ona
C. lyi
d. Owo
21. Orisi ami ohun _____ ni o wa ninu ede Yoruba
a. Meji
b. Meta
c. Merin
d. Marun-un
Oonka ni ede Yoruba lati ori aarun de ori ogowa(5-200)
21. Iro to ni ami ohun oke ni
a. U
b. U
c. R
d. L
22 . Ohun akoko ti a gbodo ko ti a ba n ko
aroko ni
a. Ifaara
b. Orúkọ
C. Akole
d. Adiresi
23. ___ ojo ni Oduduwa ati awon eniyan re
fir in lati meka de ile-ife
a. Andorun-un.
b. Ọgọ́rùn-ún
C. Aadota
D. Ogorin
24. Abikeyin Okanbi ni
a. Orangún
b. Alaketu
c. Oba Bennin
d. Qranmlyan
25. Okan ninu idagbasoke tí isakoso Oduduwa
muba ni i le-ìfẹ́ ni
a. Wahala ẹsin
b. Ise ona ati agbe
C. Ogun abele
d. Iku agbonniregun
26. Oruko eni ti o tẹ ilu Ọ̀yọ́ do ni
a. Oranmiyan
b. Orangun
C. Ons bell
d. Alaketu
27. Orirun awon Yoruba ni
a. Abeokuta
B. Ọ̀yọ́
C. Ilé ifẹ
d. Ibadan
28. Odun ti won se ai iranti Moremi ni ilé ìfẹ́ nì
A. Edi
B. Ọlọjọ́
C. Pokulere
D. Osaara
29. Lára ikulo ede Yoruba ni
A. Fun polowo oja
b. Faweli
C. Konsonanti
D. Silebu
30. Ekun iyawo je apeere literso a lóhùn ___
A. Oloro geere
b. Ewì ajemo ayeye
C. Ewì ajemesin
d. Ere onise
31. Agbegbe __ ni wọn tin sún rárá Egba
A. Ẹ̀gbá
B. Ekiti
C. Ọ̀yọ́
d. Ilesa
32. Sipeli yii ko ba akoto titun mu
A. Ọlọ́pàá
b. Tinyin
C. Yoo
d. Náà
33. Ohun akoko ti á gbodo kọ́ tí a bá ń kó aroko ni
A. Ifaara
B. Orúkọ
C. Akole
D. Adiresi
34. Ami ohun orí “eyele” ni
A. R, R, D
B. R, R, M
C. D, R, M
D. M, R, D
35. Eroja tó ń gbé aroko nìyí nii
A. Sipeli atijo
B. Asipa owe
C. Awawi asán
D. Ede to dára
36. Ní ilé Yoruba, ọjọ́ ____ ni à man sọmọ lórúko
A. Ojo Kẹ̀sán
B. Ọjọ́ kẹjọ
C. Ọjọ́ keje
D. Ọjọ́ kẹfà
37. Ọjọ́ kelo ni a sọ awon omo ibeji lórúko ni ile Yoruba ____
A. Ọjọ́ kẹjọ
B. Ọjọ́ kẹsàn-án
C. Ọjọ́ Kẹ̀wá
D. Ọjọ́ kejì
38. Lára nkan ìsò ọmọ lórúko ní
A. Aṣọ
B. Bàtà
C. Délé
D. Eja abori
39. Orúkọ amutorunwa ní ___
A. Sade
B. Kola
C. Aina
D. Dúpẹ́
40. Lára ona ti a le gba s’eda ọ̀rọ̀ orúkọ ni
A. Nípa apetunpe ọ̀rọ̀ ìṣe
B. Silebu
C. Konsonanti
D. Faweeli
41. Ọ̀rọ̀ Orúkọ ni àwọn oro wonyi afi ___
A. Ọlá
B. Alafia
C. Sugbon
D. Ẹyẹ
42. Lára nǹkan oge sise ni ___
A. Ijo jíjó
B. Iná dídá
C. Orun sísun
D. Ila kiko
43. ___ ni ibi tí àwọn àgbè tin sise
A. Ofisi
B. Banki
C. Ọkọ
D. Ilé iwosan
44. Faweeli melo ni o wa ninu ede Yoruba ___
A. 7
B. 8
C.9
D. 10
45. Ege oro ti a le pín lórí iseemi kan soso sì ni a pè ní ___
A. Foniimu
B. Akoto
C. Silebu
D. Faweeli
46. ” Mo lọ” Silebu mélòó ni ó wà nínú “mo” ___
A. Kan
B. Méjì
C. Mẹta
D. Merin
47. Ihun ọ̀rọ̀ onisilebu kan nìyí, afi ___
A. F
B. FKF
C. KF
D. KF (n)
48. F(n) túmọ̀ sí Faweeli
A. Airanmupe
B. Aranmupe
C. konsonanti
D. Ege Faweeli
49. Níbi ere Alo Apamọ́, ede n rán omode lowo lati
A. Sún dáadáa
B. Feran obi wọn
C. Ronú jinle
D. Ní oro kún ore
50. Kí ló n kọjá lójú de oba, tí kò kí oba?
A. Ojú iná
B. Agbára ọjọ́
C. Oyinbo
D. Gomina
Apá kejì
Dáhùn àwọn ìbéèrè wonyi
Dáhùn ibeere mẹta péré. Ibeere kinni se pataki
1a. Kọ́ aroko lórí “Ilé iwe mi”
1b. Kò àrọko lórí “Ọ̀rẹ́ míì tí mo feran julo”
2. Sọ itan Odùduwà ati awon ọmọ rẹ
3. Kò oonka ede Yoruba lati 1 titi de 50
4. Kọ alifabeeti ede Yoruba