Second Term Revision and Readiness Test Yoruba Primary 3 Second Term Lesson Notes Week 1

Oruko: ……………………………………………………….……… Deeti: …………………….

Ise: Ede Yoruba  

Kilasi: Oniwe Keta

 

Isoro n gbesi ni ile aro

 

  1. Ojo ti awon omode lo be ile aro wo je ojo ……………… (a) Abameta (b) Eti (d) Aiku

 

  1. …………………. Ni ohun ti awon alagbede fi maa n finna. (a) Ewiri (b) Omo owu

 

  1. Kini oruko ti a n pe irnse ti alagbe fii n mu irin ninu ina? (a) amuga (b) emu

 

(d) reeki

 

  1. Bawo ni a se maa n ki alagbede? (a) aroye o (b) aredu o (d) e mo o se o

 

  1. Kini oruko ibi ise alagbede? (a) ile aro (b) ile ita (d) ile oja

 

Onka ni ede Yoruba

 

  1. Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba – 25? (a) aarundinlogbo (b)aarundinlogoji (d) aarundinlogun

 

  1. Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba – 40? (a) ogbon (b) ogoji (d) aadota

 

  1. Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba – 15? (a) aarudinlogun (b) aarundinlogoji (d) ogun

 

  1. Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba – 20? (a) ogbon (b) ogoji (d) ogun

 

  1. Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba – 35? (a) aarudinladota(b) aarundinlogoji (d) aarundinlogun

 

 

Kika ati kiko gbolohun kekeeke:

 

  1. ……………………….ni o n di irun (a) Sola (b) Peju (d) Yemi

 

  1. …………………………ni o n foe yin (a) Kemi (b) Tayo (d) Sade

 

 

  1. ……………………………….ni o wo kaba (a) Gbemi (b) Bisi (d) Tayo

 

  1. ………………………..ni o n foe se (a) Gbemi (b) Sola (d) Wunmi

 

  1. ………………………….ni o n je eko (a) Peju (b) Bisi (d) Wunmi

 

Daruko nkan marun-un ti o wa ni inu ilu.

 

  1. …………………………………………………………..

 

  1. …………………………………………………………..

 

 

  1. ……………………………………………………………

 

  1. ……………………………………………………………

 

  1. ……………………………………………………………

 

 

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share