3RD TERM EXAM QUESTIONS PRIMARY 3 YORUBA LANGUAGE

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 

CLASS: PRIMARY 3

SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

ASA IKINI 

  • Nibo ni Alake  ba iya re lo?   (a) si odo iyasola (b) si odo iya tunde
  • Kiini iya sola sese se? (a) osese lo si ile  iwosan (b) osese bimo 
  •  Bawo ni a sen ki eni ti o ba sese bimo?  (a) Eku ise o  (b) Eku ewu omo 
  • Bawo ni a se nki eni ti o nsile? (a) ile a tura o (b) eku inawo 
  • Bawo ni a se nki alagbede? (a) emo se o  (b) aro ye o 

 

Owe Ile Yoruba 

  • Pari owe yii: Agba kii nwa loja, _______________ (a) kori omo tuntun wo  (b) ki inu obi ni
  • Pari owe yii: Bi omode ba mo owo we, ____________  (a) Owo e a mo ni  (b) A ba agba jeun
  • Pari owe yii: Ile ti a fi ito mo, ____________ (a) irin ni yoo wo  (b) ategun a gbe lo 
  • Pari owe yii:: Eni ti yoo je oyin inu apata, __________ (a) aake aro ni   (b) kii now enu aake
  • Pari owe yii: Bami na omo mi __________ (a) (a) owo dun iya e ni   (b) ko de inu olomo

 

Ipolowo Oja 

  • Oja wo ni a npolowo bayii: langbe jinna o , oroku ori ebe   (a) orisu sise     (b) alagbado
  • Oja wo ni a npolowo bayii: gbetuuru o, omi akerese, kii ndun lodo, to ba dele, adoyin    

(a) eleja tutu  (b) eleran

  • Oja wo ni a npolowo bayii: lamuruke  ___sokudale adalu     (a) onisu sise (b)elewa sise    
  • Oja wo ni a npolowo bayii: gbanjo, gbanjo, ko lo nle, ko dowo o, oyinbo wo gbese oko mi lo nse  emi  ni mo nta   (a) alaso (b) gaari
  • Oja wo ni a npolowo bayii: ______ re one re, ewoju ob eke mu ______     (a) Asaro  (b)Iyan    

 

ALO APAMO

  • Aloo, aalo, kilo koja niwaju oba ti ko ki oba, kii nio,  (a) Esinsin  (b) Agbara oko
  • Aloo, aalo opo baba alo kan lae lae opo baba alo kan laelae, ojo to ba de fila pupa, ni iku de ba kiinio (a) sigidi  (b) abela / siga
  • Aloo, aalo, ile gbajumo kiki imiera, kiini o:  (a) osan  (b) ibepe
  • Aloo, aalo, okun nho yaya, osa nho yaya, omo buuruku to rib o, kiini o:  (a) Omorugun  (b) irin
  • Aloo, aalo, gele dudu gbaje ona kiini o: (a) eera  (b) ijalo

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share