Yoruba Primary 6 First Term Examinations

Table of Contents

FIRST TERM EXAMINATION 2021/2022

CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

 

NAME:…

 

IWE KIKA: IYI ISE SISE

1. Ibo ni orisun gbogbo iwa ibaje? (a) Ile-eko (b) inu oko (d) Odede

2. Ewo ni kii se iwa ibaje ninu awon wonyii (a) ole (b) akikanju (d) ojukokoro

3. Iwa Agbeke di awokose fun awon elegbe re nitori _________

(a) iro pipa re (b) agbagun elubo re (d) iwa omoluabi re

4. Iya Agbeke fun-un ni _________ ko to bere ile-eko

(a) Aso tuntun (b) imoran (d) Ounje to dara

5. Bawo ni Agbeke se jere iwa re ni ile-eko (a) Won na-an legba (b) won fun-un ise se (d) won fun-un ni eko ofe

 

IWE KIKA: IJA KO LERE

1.Kiini Ajao fe se nigba ti Alagba Alao pariwo pe, omo naa niyi?

(a) o fe ba ehoro sare (b) o fe fun won ni ehoro (d) o fe salo

2. Won ko pati e bo o, tumo si pe

(a) won jaa ni pati e (b) won na-an daadaa (d) won fi iya je

3. Inu Alagba Alao dun nitori won _____

(a) bu Ajao (b) na Ajao (d) ko won jade

4. ______ ti Alagba Alao lo ni o je ki won ri Ajao mu

(a) ile-eko (b) kilaasi (d) ogba

5. Oga ile-eko se ileri fun Alagba Alao pe oun yoo ____

(a) sare pe won obi (b) lo si ago olopaa (d) ba gbogbo awon akekoo soro

 

LITIRESO: EWI OMOLUABI

. 1. Ninu ewi yii, a rii pe, omoluabi maa n _____

(a) siwahu (b) so yaya (d) fewo

2. Ewi yii koni pe, omoluabi a maa

(a) sepe (b) jeun ni won-tunwon si (d) woso ti ko mo

3. Omo ti yoo je asamu tumo si

(a) omo ti yoo je ologbon (b) oruko re yoo maa je asamu (d) yoo sa nnkan mu

4. Akewi yii fe ki a je ________ (a) omoluabi (b) ole (d) wobia

5. Ewi yii so pe:- a-la-je wora ni _______ (a) ole (b) wobia (d) obun

 

 

ISEDA ORO ORUKO

Seda oro oruko marun-u nipa lilo afomo ibeere: ai, bi apeere:

ai + ku aiku

 

_ 1_________________________________

__2________________________________

___3_______________________________

____4______________________________

_____5_____________________________

 

Seda oro oruko nipa lilo afomo ibeere ori, bi apeere:

oni + isu – onisu, oni + ata alata

 

1.__________________________________

__2________________________________

___3_______________________________

____4______________________________

_____5_____________________________

 

Seda oro oruko nipa lilo afomo aarin, ni: ku, si, je, ki, de, bi apeere:

ile + ki + ile ilekile

 

1__________________________________

_2_________________________________

__3________________________________

___4_______________________________

____5______________________________