Ìtàn isedale Yoruba
Subject ; Yoruba
Class : Basic 6
Term : Third Term
Week :Week 10
Previous Knowledge : Learners have previous knowledge of how the Yoruba migrated from Meca to ILE Ifè
Behavioural Objectives b By the end of the lessons, learners will be able to
- Say the founder of yorùbá land
- Explain how the Yoruba migrated and form the new Yoruba land
- Mention the children of Odùduwà
Content
- Lamurudu ni bàbá ńlá àwa Yoruba
- Ilu meeka ni Lamurudu wá láti ìbéèrè pẹpẹ, elesin iborisha nii
- Lamurudu bí ọmọkùnrin kan tí orúkọ rẹ njẹ Odùduwà (ODU TI O DA ÌWÀ)
- Odùduwà náà bí ọmọ ọkùnrin kan tí òrùlé rẹ NJẸ ỌKÀN BÍ (ÌDÈ Ó ṢE RÒ AKE)
- Okanbi fe Ọmọnide ni ìyá wo, wọn bí ọmọ méjì, láti ọmọ Okanbi là tí tán kalẹ
- Okanbi kú síwájú Odùduwà, Odùduwà ni ó tó àwọn ọmọ wonyi
- Nígbà tí tí wọn dàgbà, wọn pín ogún bàbà wọn, ká kúkú wọn sì lọ tèdó sí ikú kankan
- Lamurudu ni abore kan tí ó man nba bo àwọn òrìṣà rẹ, wọn má ń bá ṣe ọdún iborisha, orúkọ abore rẹ ni Asara
- Asara yìí bí ọmọ ọkùnrin kan tí orulo rẹ njẹ Buraimoh, inú ẹṣin ìbòrí sá ni wọn bíi sì
- Nigbati Buraimoh dàgbà, tí òye yee, ó kéde esin fún àwọn ará ìlú
- Ó ní kí wọn má tẹle ìsìn àwọn bàbà òun, ohun tí wọn bo ti kólé sors
- Lọ́jọ́ kan, leyin ti àwọn elesin aborisa yìí pariwo ọdún wọn, Buraimoh kò gbogbo ère òrìṣà wọn jo, ó sì dáná sún wọn
- Inú bíi àwọn elesin iborisa yìí, wọn si fii ìjà peeta, nínú rògbòdìyàn ìjà ẹṣin yìí ni Lamurudu kuu sì
- Wọn lé Odùduwà kúrò ní ìlú Mekka pelu awon eniyan rèé.
- Odidi adorun ojo ni Odùduwà fi rìn láti ìlú meeka kí ó tó dé ilé iife tí ó tèdó sii
- Ní ilé ìfẹ́, Odùduwà bá SETILU nibe, AGBONMIREGUN (ojogbon imo àti ọgbọ́n)
- Ní ilé ìfẹ́, wọn fi Odùduwà jọba Yoruba, èyí rìn ṣeé OONI àkọ́kọ́
- Ilé ìfẹ́ yìí ni àwa ọmọ Yoryba gba gbọ̀ gege bí orírun wà rírí di òní oloni
- Àwọn elesin musulumi tún lépa Odùduwà làti paa
- Pẹ̀lú àti leyin SETILU, Odùduwà segun wọn, wọn gba iwe ti wọn dii ni gbìn rìn sílè lowo wọn, a npe ni ÌDÍ