Èdè Yorùbá : Àṣà Ìran ra ẹni lowo ni ile Yorùbá

Àwọn ọ̀nà wonyi ni àwọn Yoruba má ń gba láti rán ara wọn lowo ni igba ìwáṣẹ̀

 

Asa Iranra Eni lowo- Ajo, Esusu, Egbe Alafowosowopo

1. Ọwẹ̀ : eleyi tún mo sì ìṣe ọkọ tí a má bàa ara wa see
2. Àárọ̀
3. Àjò didia
4. Esùsú
5. Àrọko dodo
6. San die die
7. Owo èlé
8. Oogo
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share
Use the search box to search for any topics or subjects that you want