Akole:onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogun 

Pry one

Ose kefa

Akole:onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogun

1-Ookan

2-Eeji

3-Eeta

4-Eerin

5-Aarun

6-Eefa

7-Eeje

8-Eejo

9-Eesan

10-Ewaa

11-Okanla

12-Ejila

13-Etala

14-Erinla

15-Aarundinlogun

16-Eerindinlogun

17-Eetadinlogun

18-Ejidinlogun

19-Okandinlogun

20-ogun-un

 

Ise kilaasi

 

Kinni oruko awon nomba yii ni ede yoruba

 

1.11(a)etala (b)okanla

 

2.13(a)okanla (b)etala

 

3.15 (a)arundinlogun (b)arundinlogbon

 

4.12 (a)erinla (b)ejila

 

  1. 14 (a)ejila (b)erinla

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *