onka ni ede Yoruba lati ori aarun de ori ogorun(5-100

Pry four

Ose kinni

Akole:onka ni ede Yoruba lati ori aarun de ori ogorun(5-100)

5-Aaron

10-Eewa

15-Aarundinlogun

21-16-Erindinlogun

17-Etadinlogun

18-Ejidinlogun

19-okandinlogun

20-Ogun

21-Okanlelogun

22-Ejilelogun

23-Etalelogun

24-Erinlelogun

25-Arundinlogbon

26-Erindinlogbon

27-Etadinlogbon

28-Ejidinlogbon

29-Okandinlogbon

30-Ogbon

31-okanlelogbon

32-ejilelogbon

33-etalelogbon

34-erinlelogbon

35-Aarundinlogoji

36-erindinlogoji

37-etadinlogoji

38-ejidinlogoji

39-okandinlogoji

40-Ogoji

 

Ise kilaasi

Kinni oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba

 

1.32 (a)ejilelogbon (b)ejilelogun

 

2.35 (a)arundinlogun (b)arundinlogbon

 

3.37 (a)etadinlogoji (b)etadinlogbon

 

4.40 (a)ogbon (b)ogoji

 

5.38 (a)ejindinlogoji (b)ejindinlogun

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *