Yoruba Examination Second Term Basic 6

Yoruba five

Koa won gbolohun wonyi sile ki o fala si idi oro – ise ti o wa ninu won.

  1. Aja ojo gbe egungun eran.
  2. Bola je eba.
  3. Oluko n ka iwe.
  4. Akekoo n pa ariwo.
  5. Sade n fo aso ile – iwe re.[mediator_tech]

Ewo ni eroja idana ninu awon nnkan wony

  1. Okuta , Iyo , Eniyan.
  2. Isu , Igbale ,Obe.
  3. Iwe , Baagi , Owo
  4. Efo , ila , Oti.
  5. Ataare , Epa , Mongoro

Bawo ni awon Yoruba se n awon osu wonyi

  1. January
  2. February
  3. March
  4. April
  5. May

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share
Tags: