Ogun tí nsọ ẹ̀gbọ́n d àbúrò…

1. Ogun ti nso egbon d’aburo mo da pada lori akobi mi.

2 . Majemu ikoro lori akobi mi, Oluwa ba mi baje.

3. Akose igi mi laye ma je ko pare mo mi loju.

4. Ade agba ti akobi nfi nse ogo laye Oluwa fide omo mi lori.

5. Iwo akobi mi, mo ba irin ajo aye re soro ki o rin wonu ogo irorun ati alafia lo. 6. Epe to ma nja akobi, mo fi ikunle abiyamo dapada. (Amin)w

.

Someone might need this, Help others, Click on any of the Social Media Icon To Share !