Second Term Examination Yoruba SS 1 Second Term Lesson Notes

SECOND TERM EXAMINATION

Subject: YORUBA Class: SS2 Time:2hrs

Ka ayoka isale yi, ki o si dahun ibeere ti o te le.

Owo ti ada mo lo n kan ada leyin. Se oladejo ti feran ise ode ju, to bee ti eni kan ko le so boya inu igbo ni o n gbe tabi ilu. Ni irole ojo kan, O pe Supo omokunrin re kan soso ti o bi pe ko niso loko lati lo mu isu, o so pe ohun naa n bo.

Supo mu igba, o gbona oko lo. Ni oju ona, supo fe se gaa, kaka ki o wo inu igbo lo, ori igi ni o mu gun lati lo yagbe.

Oladejo gbera ni ile, o gbe ibon re ati apo ode re pelu ero lati wa eran igbe ti won yoo fi je iyan.

Asiko ti supo n sokale lati ori igi ni Dejo de be, kini eyi? Obo ni tabi ijimere orisii eranko ti o le je, ni o wa si okan re sugbon ewo ni ki I se obe ni o fi pari ero re.

Dejo tan ina ran ilasa, gbo sa ti o gbo, ibosi oro o! lo tele e lati enu supo. Supo subu lule, o na gbalaja. Jebete gbe omo le Dejo lowo, o bere si i sun ekun ti ko ba a mo.

IBERE EWO NIDAHUN

  1. Kini ero Dejo ni pa “ewo ni kii se obe”? ki o sa ti pa (A) eran yoo wu ti ise (B) ijimere (D) obo (E) obo tabi ijimere
  2. Kin ni o se iku pa supo? (A) aigboran (B) are kare (C) baba re (D) omugo
  3. “se gaa” ninu ayoka yi tumo si (A) gun igi (B) yagbe (C) peran (D) sere
  4. “ owo ti ada mo lo n kan ada leyin tumo si (A) ise ti ada mo se lo n kan ada leyin (B) ise sise ada lo n pa ada (C) ohun ti a ba mo se ju lo n ko ba ni (D) ounje ti a ba je lo n ko ba ni
  5. Ki ni ilasa tumo si (A) aara (B) agogo (C) ibon (D) fere
  6. A maa ri gbolohun “ipade wa bi oyin” ninu aroko (A) alalaye (B) onileta (C) asotan (D) asariyanjiyan
  7. Leta gbefe ni leta si (A) alejo (B) arabirin (C) oga ile ise (D) olootu
  8. Ori oro to je mo aroko asapejuwe julo ni (A) ija olopaa ati awon akekoo ijeta (B) ile iwe mi(C) riba (D) owo koko
  9. Ninu “emi iba lo sugbon ko si owo” sugbon je (A) oro aponle (B) oro asopo (C) oro atokun (D) oro eyan
  10. Oro ise ninu “Funke ta eran nla” ni (A) Funke (B) eran (C) ta (D) nla
  11. “Nla” ninu “Foluke ta eran nla” je apeere oro (A) apejuwe (B) aponle (C) oruko (D) ise
  12. “Yemi ti sun fonfon nigba ti mo de” fonfon je (A) oro apejuwe (B) oro aponle (C) oro atokun (D) oro asopo
  13. “Yala e lo soja tabi e ko lo soja e o jiya” oro asopo ti o wa ninu gbolohun yi ni (A) e,o (B) e,lo (C) lo,tabi (D) yala,tabi
  14. Oro aropo oruko ti o wa ninu gbolohun “Emi ni mo ran an” ni (A) emi,ni (B) ni,mo (C) mo,ran (D) mo,an
  15. Oro aropo afarajooruko ni (A) emi, awon, a(B) emi, awon, oun(C) eyin, oun, iwo
  16. Isori oro ti o se dandan, lati wa ninu gbolohun ni (A) oro apejuwe (B) oro aropo oruko (C)oro ise (D) oro oruko
  17. Iparoje je yo ninu (A) alakaa (B) aroorun (C) eleja (D) ileewe
  18. Igbese fonoloji wo lo mu “dara” di “daa” (A) ankoo faweli (B) aranmo (C) iparoje (D) iyopo faweli
  19. Foran ihun ti ati maa n pa iro konsonanti je ni (A) apola oruko (B) oro atokun (C) oro oruko (D) eyo oro

Tumo awon oro yi si ede Yoruba

  1. Yinka cannot do without taking her breakfast tumo si (A) Yinka feran ounje aro (B) Yinka ko le se lai je ounje aaro (C) Yinka feran ounjr aaro jije (D) Yinka ko le se ko ma jeun
  2. Itumo “Health is Wealth” ni (A) alaafia atoro ogba ni (B) alaafia tayo (C) ilera loro (D) alaafia tayo
  3. “The cat was let out of the bag” tumo si (A) asiri tu (B) epa ko boro mo (C) ologbo naa ti kuro ninu baagi (D) won ti tu ologbo naa kuro ninu baagi
  4. Ona kan Pataki ti Yoruba fi n mo omoluabi ni nini (A) aso (B) ewa (C) itiju (D) owo
  5. Okan ninu awon wonyi kii se eroja omoluabi (A) ibowo fun agba (B) itiju (C) nina owo karimi (D) ifarabale
  6. Okan ninu awon yi je eewo fun baale ile. Baale ile ko gbodo (A) je odaju eniyan (B) lo gbe eyin odi (C) lo si irin ajo (D) ma pe loko
  7. Ibi ti alejo gbodo lo tara ti ile ba su si ilu kan ni aye atijo ni ile (A) oba (B) ogboni (C) oloye (D) olori adugbo
  8. Ewo ni kii se omo iya awon iyoku (A) ajiroba (B) baameto (C) basorun (D) bobagunwa
  9. Bi alagbara bii babalawo tabi onisegun ba dese jibiti lilu ni ilu ijiya ti o tosi ni (A) fifi oro le e kuro ni ilu (B) gba ohun ini re (C) ju u si ewon (D) mu un san owo itaran
  10. Ijiya ti o to si adigunjale ti o mu itaje sile lowo ni (A) mimu lo si mogun (B) lile kuro ni ilu (C) tita odaran lepe (D) gige apa adigunjale
  11. Ijiya ti a fi n le oba kuro lori ite ni (A) akaba lilo (B) igba sisi (C) dide mo okun (D) kirikiri

APA KEJI

Dahun ibere meta abala yi sugbon nomba waanu se Pataki

  1. Ko aroko ti ko din ni 360 eyo oro lori okan ninu koko wonyi
  2. Ogba ile eko mi
  3. Ijamba kan ti o soju mi
  4. Ipa ti epo pupa ko lawujo wa
  5. Ko leta si egbon re kan ti o wa ni orile ede miran lori bi ise olopaa ti ri ni orile ede Naijiria
  6. Kin ni oro aponle?

b. Ko gbolohun merin, ki o si fa ila si oro aponle inu won

  1. To ka si iwa omoluabi marun ti o mo
  2. Toka si ijiya ti o to si iwa odaran yii ni aye atijo
  3. Sise eke ii.agbere sise iii. Eni ba tori ebi jale iv. Gbomo gbomo

v. irenije, oba ilu ti ko ka ara ilu si mo

  1. Ki ni itumo akanlo ede wonyi?

I. Gbe iku ta . ii. Ta ile nipa. Iii. Ru eti omolangidi . iv. Kokoro wa leti efo. V. Gbelepawo .

  1. kini itumo oro wonyii? a. idi-igi-idi-igi . b. ori-o-jori.

ii. di awon alafo wonyii.

  1. _______ ni o n se eto ogun pipin ni awujo Yoruba.
  2. ______ je okan lara ajemogun lawujo Yoruba.
  3. Pari owe yii “ gbede bi ogun iya. ___________.

SECOND TERM EXAMINATION

Subject: YORUBA Class: SS 1 Time:2hrs

Ka ayoka isale yi ki o si dahun ibeere ti o tele

Igba ikore je igba ti o kun fun ayo ni aarin awon Yoruba, bi o tile je pe igba ogbin ti o siwaju ikore mu wahala lowo. Igba ogbin ni agbe n san igbo, won si n ko ile, won si n gbin orisiirisii eso, lehin naa won a ro oko, won a si tun ma se itoju irugbin naa ki kokoro ati koriko ma ba irugbin naa je titi asiko ikore.

Igba ikore maa n mu ayo lowo nitori ni asiko ikore ni ire oko gbogbo maa n wole, nipa bee ounje maa n po yanturu.

Igba ikore ni odo maa n gbe, ti awon apeja maa n pa eja lopolopo. Igba ikore yii kan naa ni awon ode si maa n ri eran pa bakan naa.

Igba ikore maa n je igba ti odun maa n lo si opin, gbogbo eni ti o fi ara sise lati ibere odun si maa n reti isimi, ohun ti o mu ayo lowo julo lasiko yi ni wi pe gbogbo molebi nile- loko, leyin odi maa n peju pese nile. Ohun tun o tun n fa ipeju pese won ni wi pe lasiko yii ni orisiirisii ayeye maa n waye bii isinku, igbeyawo abbl.

Leyin popo sin sin wonyi ni onikaluku won yoo pada si ibugbe re fun ipalemo odun miran.

IBERE EWO NIDAHUN

  1. Igba ikore tumo si igba ti a n (A) gbin irugbin (B) je ere oko (C) ko ire oko (D) pa ile mo fun odun tun tun
  2. Ewo ni ko si lara ise ti agbe n se lakoko ogbin? (A) gbigbin orisiirisii eso (B) igbo sisan (C) ile kiko (D) ikore irugbin
  3. Kini o mu ayo lowo julo ni asiko ikore? (A) eja maa n po yanturu (B) eran a maa po yanturu (C) orisiirisi ayeye maa n waye (D) pipeju pipese molebi nile loko leyin odi
  4. Igba wo lo mu inira lowo fun awon agbe? (A) ogbin (B) ikore (C) ipalemo fun odun tuntun (D) igbo sisan
  5. Orisii igba meloo otooto ni alayoka menuba ninu ayoka yi (A) meji (B) meta (C) merin (D) marun
  6. “ijamba oko kan ti o soju mi” je aroko (A) ajemo isipaya (B) oniroyin (C) asapejuwe (D) alaye
  7. “Gbogan ilu mi” je mo aroko (A) oniroyin (B) asapejuwe (C) ajemo isipaya (D) onisorogbesi
  8. Awori je eka ede ti won n so ni ipinle (A) eko ati ogun (B) osun ati oyo (C) ogun ati oyo (D) oyo ati ondo
  9. Eka ede ti o sunmo Yoruba ajumolo ju lo ni (A) awori (B) oyo (C) eko (D) egba
  10. Imo eka ede le mu _________ wa si aarin eya Yoruba (A) ayo (B) ife (C) irepo (D) Alafia
  11. Imo eka ede le yo eniyan kuro ninu ________ (A) isoro (B) wahala (C) ibanuje (D) itiju
  12. Gbolohun meji ti a seda lati ara “Olu korin o si n jo” ni (A) Olu n korin, Olu n jo (B) Olu n korin, osi n jo (C) Olu korin, Olu n jo (D) Olu korin, Olu jo
  13. “Sade mu emu” je gbolohun (A) afibo (B) alakanpo (C) eleyo oro ise (D) asinpo
  14. Gbolohun abode gbogbo ni (A) abo (B) eyan (C) oro aponle (D) oro ise
  15. Ewo ni gbolohun olopo oro ise (A) Adio ta agbado lanaa (B) baba ge igi loko (C) Bola ra iresi tore (D) iya ro amala nile
  16. “Olu ti mu igi naa wa” je apeere gbolohun (A) ibeere (B) alaye (C) ase (D) atokun
  17. ‘Yara pada” je gbolohun (A) ibeere (B) alaye (C) ase (D) atokun
  18. Ila kookan ti a fa lati ereke de isale re ni ila (A) egba (B) ife (C) igbomina (D) ondo
  19. Ila ti imo olaju ti fi eri tembelu ni ila (A) abe obinrin (B) aya (C) abe okunrin (D) oju
  20. Ila meta meta ti o pade ni enu ni a n pe ni (A) yagba (B) gombo (C) keke (D) ture
  21. Pari owe yi “Dandogo” (A) koja abinuda (B) ni olori aso (C) ni aso amujoye (D) ni aso agbalagba
  22. Ewo ni o je mo oge sise okunrin (A) eyin pupa (B) irun didi (C) irun kiko (D) ori fifa
  23. Ewo lo je mo oge sise obinrin (A) aso wiwo (B) fifari apa kan (C) irun didi (D) osu dida
  24. Aso imurode okunrin ni (A) ade (B) iteko (C) oyala (D) tobi
  25. Gberi ode je aso (A) awon ode (B) awogbele ode (C) egbe ode (D) ise ode
  26. Asiko ti ipolowo oja maa n wopo laarin igboro ni (A) ale patapata (B) asaale (C) owuro kutu (D) idaji
  27. Kobegbemu ninu ona ipolowo oja ni (A) aago lilu (B) awin (C) idogo (D) isiwo
  28. Ona ipolowo oja ni (A) ijakadi (B) ikiri (C) ipolowo (D) ipate
  29. “She kicked the bucket” tumo (A) omobinrin naa daku (B) omobinrin naa gba peeli ni boolu (C) omobinrin naa ku (D) omobinrin naa gbe peeli nile
  30. “Manner maketh man” tumo si (A) iwa loba awure (B) iwa ni nnkan (c) iwa rere leso eniyan (D) iwa se Pataki

SS 2 THIRD TERM YORUBA LESSON NOTES

APA KEJI

Dahun ibere meta ni abala yii, sugbon nomba waanu (1) se Pataki

  1. Ko aroko ti ko din n iota le loodunrun (360) eyo oro lori okan ninu koko wonyi.
  2. Ayeye odun keresimesi ti o koja
  3. Oluko ede Yoruba ni ile iwe mi
  4. Ko leta si ore re kan ti o wa ni ile iwe miran lori idije onile jile ti o waye ni ile iwe re lai pe yi
  5. Pelu apeere meji meji, kini gbolohun
  6. Ase ii. Ibeere iii. Alaye iv. Ka ni v. akiyesi vi. Akiyesi alatenumo
  7. Kini oge sise?

b. Daruko orisii ila merin

c. Toka si sitai aso okunrin marun ni aye atijo

  1. Tumo gbolohun wonyi si ede Yoruba .
  2. My heart sank , ii. A twinkle of an eye iii. You cannot eat your cake and have it. iv. A stone heart v. A child is the father of man
  3. Knii itunmo akanlo ede wonyi
  4. Okete boru ii. Gbewiri iii. Ojo kutoto iv. Edo oju v. firu fonna

AKAYE ÀYỌKÀ

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share