Orin ibile fún ayẹyẹ

Ipin Kiini: Orin Ibile Fun Ayeye
Ko okan ninu orin ibile fun ayeye

Ipein Keji
Daruko marun-un igbese asa igbeyawo ni aye ode oni, ki ose alaye okan ninu won ni soki

Ipin Keta: Awon Osu Inu Odun
Daruko marun-un osu inu odun, ki o so, oruko akoko osu Kankan

Orin ibile fún ayẹyẹ

Ipin Kerin: Oro Ise Ninu Gbolohun
Ewo ni apeere oro ise ninu awon gbolohun wonyii
Wale je eba ni ale ana (a) ana (b) je
Kola mu emu ni oko (a) oko (b) mu
Isola pa eran ti o tobi (a) pa (b) eran
Yetunde ra iru ati iyao ni oja (a) oja (b) ra
Yemi sun si ori ibusun re (a) sun (b) ibusun

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share
Use the search box to search for any topics or subjects that you want