Tag: JSS 2

Implications and effects of Drug Abuse

FIRST TERM E-LEARNING NOTE   SUBJECT: SOCIAL STUDIES    CLASS: JSS 2   TOPIC:  Implications and effects of Drug Abuse     TERM: FIRST TERM    WEEK: WEEK 3 PREVIOUS KNOWLEDGE: Pupils have previous knowledge of        Drug Abuse     BEHAVIUORAL OBJECTIVES: At the end of the lesson, pupils should be able

Drug Abuse

FIRST TERM E-LEARNING NOTE   SUBJECT: SOCIAL STUDIES    CLASS: JSS 2   TOPIC:  Drug Abuse     TERM: FIRST TERM    WEEK: WEEK 2   PREVIOUS KNOWLEDGE: Pupils have previous knowledge of        DRUG TRAFFICKING     BEHAVIUORAL OBJECTIVES: At the end of the lesson, pupils should be able to Define abuse

DRUG TRAFFICKING

FIRST TERM E-LEARNING NOTE   SUBJECT: SOCIAL STUDIES    CLASS: JSS 2   TOPIC:  DRUG TRAFFICKING     TERM: FIRST TERM    WEEK: WEEK 1   PREVIOUS KNOWLEDGE: Pupils have previous knowledge of        QUALITIES AND BEHAVIOUR THAT ENHANCE FRIENDSHIP     BEHAVIOURAL OBJECTIVES: At the end of the lesson, pupils should be

Kiko Yoruba ni ilana Akoto Ode-Oni

OSE KEWAA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: Kiko Yoruba ni ilana Akoto Ode-Oni Iyato ti o de ba iro konsonati ninu akoto ode-oni Sipele Atijo                                Sipele Ode Oni Iddo                                    Ido Otta                                    Ota

IYATO TI O DE BA SIPELI FAWELI

OSE KESAN-AN EKA ISA:EDE AKOLE ISE: AKOTO Akoto je ona ti a n gba ko sipeli awon oro ede Yoruba sile lona to boju mu lode oni. Sipeli atijo ni ona ti a n gba ko awon oro ede Yoruba sile ki ijobe orile-ede Naijiria to fi owo si ona tuntun ti a le gba

ASA ISOMOLORUKO

OSE KEJO EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKAYE OLORO GEERE Ayoka kika-yoruba fun sekondu olodun meta akeko iwa keji, lati owo ola m. ajuwon etal (2014). Pg43. Itosona- Ka ayoka yii ki o si dahun awon ibeere to tele. Ni asale leyin ti aduke ati iya re je oka ati efo riro tan, iya re

AKAYE OLORO GEERE

OSE KEJE EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKAYE OLORO GEERE. Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yeni yekeyeke Igbese ayoka kika a.kika ati mimo ohun ti ayoka naa dale lori sise itupale ayoka ni finifinni fifi imo ede, laakaye ati iforabale ka ayoka naa sinu dida

Onka Yoruba (300 – 500)

OSE KEFA Eka Ise:- Ede  Akole ise: onka Yoruba (300-500)  Onka Yoruba lati oodunrun de Eedegbeta Figo 300 Oodunrun  305 Oodunrun ole-marun-un 310 Oodunrun ole-mewa  315 Okooleloodunrun odunarun-un  320 Okooleloodunrun  325 Okooleloodunrun ole-marun-un  330 Okooleloodunrun ole-mewaa 335 Ojileloodunrun odin marun-un  345 Ojileloodunrun ole-marun-un 350 Ojileloodunrin ole-mewaa  360 Otaleloodunrin  365 Otaleloodunrun ole-marun-un  370 Otaleloodunrun ole-mewaa 375

Onka Yoruba (101 – 300)

OSE KARUN – UN EKA ISE:    EDE AKOLE ISE:    Onka Yoruba (101 – 300) Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun.   Onka ni bi a se n siro nnkan ni ilana Yoruba.   Onka Yoruba lati ookanlelogorun-un de eedegbeta ONKA FIGO ONKA NI EDE YORUBA