YORUBA LANGUAGE PRIMARY 4 FIRST TERM EXAMINATION 

FIRST TERM EXAMINATION 

CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

  1. Iwe Kika: – Asinnu Ole
  2. __________ ni oruko oja ilu pokii (a) ikilo (b) ayelu
  3. Ohun ti o se akoba fun pokii nip e (a) o nra epa je (b) o ni ore pupo
  4. __________ ni o bu pokii pe: Lanboroki, oju re jaa (a) Ore pokii kan (b) Aladugbo pokii kan
  5. ___________ ni eni ti won fa omo ti o sale gan-an fun lati da seria fun-un (a) Olopaa (b) Ara Oja Ayelu
  6. Kini oruko aladugbo pokii ti o mu pada sile? (a) Alao (b) Ajayi
  7. Ounje Kari Aye: Iwe Kika
  8. ______ ni won fi nse gaari (a) isu (b) gbaguda
  9. _________ ni won fi nse Amala dudu (a) Agbado (b) Isu
  10. ___________ ni won fi nse ogi (a) Ewa (b) Agbado
  11. ___________ ni won fi nse obe gbegiri (a) Agbado (b) Ewa
  12. _______ ni won fi nse guguru (a) Iresi (b) Agbado
  13. Iwe Kika: Adubi Ati Iya Re
  14. Omo melon i iya adubi bi? (a) omo meta (b) omo kan
  15. Iru owo won i Awele nse? (a) o nta eja (b) o nta isu
  16. Ona won i Olorun fi pon adubi le? (a) Adubi gbe odo oyinbo oniwaasu (b) Adubi ba iya re ta eja
  17. Kini o gbe Adubi de odo oyinbo oniwaasu (a) Ko mo eniyan si ilu naa (b) Ise omo odo
  18. Kini ko je ki Awele le paaro aso bi awon elegbe re? (a) Ere oja re ko po (b) Ko feran oge
  19. Ilu
  20. Awon ________ lo ni ilu bata (a) oni sango (b) elesu
  21. Awon ________ lo ni ilu agree (a) onifa (b) ologun
  22. Awon ________ lo ni ilu ipese (a) olobatala (b) onifa
  23. Awon _______ lo ni ilu igbin (a) oloya (b) olobatala
  24. Awon _________ lo ni ilu gbedu (a) Oba ati ijoye (b) Baba lawo