FIRST TERM EXAMINATION 2020/2021 CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

FIRST TERM EXAMINATION 2020/2021

CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

 

NAME:…………………………………………………………………………………

 

IWE KIKA: ASIMU OLE

1.) __________ ni oruko oja ilu pokii (a) ikilo (b) oroorun (d) ayelu

2.) Ohun ti o se akoba fun pokii ni pe _____________

(a) o ni ore pupo (b) o nra epa je (d) o nlo si ile eko

3.) Eni ti o bu Pokii pe “Lanboroki, oju re jaa na” ni __________

(a) Aladugbo Pokii kan (b) Ore Pokii kan (d) Obi Pokii

4.) _______________ ni eni ti won fa omo ti o jale gan’an fun lati da seria fun-un

(a) Ore Pokii (b) ara oja ayelu (d) Olopaa

5.) Kini oruko Aladugbo Pokii ti omu-un pada sile? (a) Alao (b) Adigun (d) Ayinla

 

OUNJE KARI AYE: EGE ATI AGBADO

i.) Eni ti o so pe paki ni won fi nyan gaari ni _________ (a) Bunmi (b) Wale (d) Baba

ii.) Eon la nfi paki se ninu awon nnkan wonyii (a) kango (b) Abari (d) fufu

iii.) Bi agbado ba parade, a maa di ____________ (a) ogi (b) fufu (d) lafun

iv.) Ewo ni kii se ooto?

(a) Igi ege ni a maa ngbin (b) agbado ni a fi nse fufu (d) A maa nse iro ege kan je

v.) Ko ounje meji ti a maa nfi agbado se

(a) _______________________________ (b) _______________________________

 

IWE KIKA: ADUBI ATI IYA RE

1.) Omo melo ni Iya Adubi bi? (a) omo meta (b) omo kan (d) omo meji

2.) Iru owo wo ni Awele nse (a) onta isu (b) o nta ounje (d) o nta eja

3.) Ona wo ni Olorun lo fi pan Adubi le? (a) Adubi gbe odo oyinbo oniwaasu

(b) Adubi ba iya re ta eja (d) Adubi lo yunifasiti Ibadan

4.) Ki ni gbe Adubi de odo oyinbo oniwaasu

(a) O fe kawe sii (b) Ise omo odo (d) ko mo eniyan kankan

5.) Kin ni koje ki Awele le paaro aso bi awon elegbe re

(a) O ya obun pupo (b) ko feran oge (d) ere oja re ko po

 

 

ILU LILU

1.) Awon ___________ lo ni ilu bata (a) onisango (b) oloya (d) olode

2.) Awon ____________ lo ni ilu ipese (a) ogun (b) Babalawo (d) elegun

3.) Awon ____________ lo ni ilu igbin (a) olobatala (b) ologun (d) olode

4.) Awon ___________ lo ni ilu Agere (a) ogun (b) sango (d) oya

5.) Oruko wo ni a npe iran onilu (a) ayan (b) oje (d) apon

 

IWE KIKA: AARO LOJO

1.) Igba ti o dara ju lati mura sise ni igba __________ (a) ogbo (b) ewe (d) oru

2.) Awon ti o nfi ewu ori sise to leje __________ ni aaro aye won

(a) ole (b) oluko (d) onisowo

3.) Ohun ti o sele si eni ti o nse ole nigba ti o ba dogba ni ki o di _____

(a) dokiita (b) alaaru (d) kafinta

4.) Oro miran fun igba ogbo ni igba __________ (a) omode (b) odo (d) arugbo

5.) Eni ti ko ba se ise yoo (a) jale (b) dolowo (d) kole

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share