YORÙBÁ JSS 2 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ

YORÙBÁ JSS 2 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ
ÕSÊ
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÀMÚŚE IŚË
1.
ÈDÈ: Sílébù Èdè Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.
Oríkì sílébù .
2. Ìhun
sílébù (F, KF, Kos (N)
3.
Pípín õrõ sí sílébù 
OLÙKÖ
1. Sô
oríkì sílébù 
2. Śe
àlàyé ìhun sílébù
3. Sç
õpõlôpõ àpççrç pínpín õrõ sí sílébù sójú pátákó
AKËKÕÖ
1. Têtì
sí àlàyé olùkö
2. Śe
àpççrç pípín õrõ sí sílébù fúnra rê
3. Kô
ohun tí olùkö kô saju pátákó sínú ìwé
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Pátákó
ìkõwé.
2.
ÀŚÀ: Êsìn Ìbílê Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.
Pàtàkì Êsìn Láwùjô Yorùbá
2.
Ìgbàgbö Àti Èrò Àwôn Yorùbá Nípa Olódùmarè
3. Ipò
Olódùmarè
4.
Òrìśà Ilê Yorùbá
5. Êsìn
òde òní:
*
Mùsùlùmí
*
Ômôlëyìn Jésù
OLÙKÖ
1. Śe
àlàyé ipa ti êsìn ń kó láwùjô
2. Śe
àlàyé ipò Olódùmarè nínú êsìn
3.
Śàlàyé nípa àwôn òrìśà ilê Yorùbá àti bí a ti ń sìn wön.
4. Śe àlàyé àjôśe àárin
àwôn çlësìn ìbílê, Mùsùlùmí àti Ômôlëyìn Jésú
AKËKÕÖ
1. Sô ohun ti wön mõ nípa
êsìn ìbílê Yorùbá àti êsìn ìgbàlódé
2. Jíròrò nípa àjôśe
Olódùmarè, àwôn òrìśà àti olùsìn wôn.
3. Jíròrò lórí ìjà êsìn
àti bí a śe lè dékun rê.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Àwòrán àwôn çlësìn
oríśìí mëtêêtà níbi ìsìn.
2. Fídíò
3. Sinimá
3.
LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn Ìwé Ìtàn Àròsô Ôlörõ Geere
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.
Ìsônísókí ìśêlê inú ìtàn abáyému
2. Êkö
àti kókó õrõ tó súyô àti ìbáyému õrõ tó ń lô láwùjô, (bí àpççrç ipò/ ìpín
obìnrin láwùjô, ìkôlura êsìn, ômôlúàbí, ìtöjú àyíká, ìlera, ààrùn éèdì/
rômôlöwölësê abbl)
3. Êdá
ìtàn àti ìfìwàwêdá
4. Ìlò
èdè:
(a) Ônà
èdè
– Àfiwé
– òwe

Àkànlò èdè
(b)
Àwítúnwí

Ìfìrómõrísí

ìfohungbohùn abbl  
OLÙKÖ
1. Śe
ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn náà dálé.
2. darí
akëkõö láti tún ìtàn sô
3. Śe
àlàyé lórí àwôn kókó-õrõ tó súyô àti ìbáyému wôn
4. Śe
àlàyé nípa àwôn êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn
5. darí
ìjíròrò nípa ìlò èdè nínú ìtàn náà.
AKËKÕÖ
1. Ka
ìwé náà
2.  tún ìtàn náà sô ní sókí
3.
jíròrò lórí kókó-õrõ inú ìwé náà àti ìbáyému wôn
4. Tëtí
sí àlàyé olùkö nípa êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn.
5. Kópa
nínú ìjíròrò lórí ìlò èdè.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Ìwé
tí a yàn fún kíkà.
2.
Àwòrán díê lára ìśêlê tó köni lëkõö nínú ìwé náà.
4.
ÒÝKÀ: Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200). Kíka owó Náírà
ÀKÓÓNÚ IŚË
Òýkà
láti Oókanléláàádöjô dé igba (151-200). Òýkà owó náírà b.a. náírà kan, náírà
méjì, ogún náírà, ôgbõ náírà abbl.
OLÙKÖ
1. Tö
àwôn akëkõö sönà láti ka òýkà – Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200).
2. Śe
àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún.
3. Tö
akëkõö sönà láti ka owó náírà pêlú òýkà Yorùbá.
AKËKÕÖ 
1. Ka
òýkà láti Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200).
2. Dá
òýkà tí a kô sójú pátákó mõ  ní õkõõkan
3. Dá
owó náírà mõ àti bí a śe ń pè wön ní ìlànà òýkà Yorùbá
4. Kô
òýkà tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1.
Kádíböõdù tí a kô òýkà láti Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200).
2.
Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí.
3. Owó
náírà lóríśiríśi.
5.
ÈDÈ: Oríśiríśi Gbólóhùn (Ìhun)
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.
Oríkì Gbólóhùn
2. Oríśiríśi
Gbólóhùn
*
Alábödé
*
Alákànpõ
* Oníbõ
OLÙKÖ
1. Fún
gbólóhùn ní oríkì
2. Śe
àlàyé ìhun õkõõkan àwôn oríśi gbólóhùn mëtêêta
3. Śe
àpççrç õkõõkan irú àwôn gbólóhùn náà, kô wön sára pátákó, kí o sì kà wön fún
akëkõö.
4. Darí
akëkõö láti śe àwôn àpççrç mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö śe.
AKËKÕÖ
1. Tëtí
sí àlàyé olùkö nípa oríkì gbólóhùn àti ìhun õkõõkan àwôn oríśi gbólóhùn
mëtêêta náà.
2. Da
àwôn àpççrç tí olùkö kô sára pátákó kô sínú ìwé rç.
3. Pe
àwôn gbólóhùn náà têlé olùkö
4. Śe
àwôn àpççrç mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö śe.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
 • Kádíböõdù tí a kô àpççrç gbólóhùn alábödé, oníbõ
  àti alákànpõ sí.
6.
ÈDÈ: Àmì Ohùn
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.
Oríkì àmì ohùn
2.
Àlàyé lórí oríśi ohùn Yorùbá mëtêêta àti àmì wôn
i. Ohùn
àárin – (a kì í fi í hàn lórí õrõ)
ii. Ohùn ìsàlê –
iii. Ohùn òkè –    
3.
Fáwëlì àti oríśiríśi àmì ohùn kõõkan lórí fáwëlì kõõkan. Bí àpççrç: à, a, á,
è, e, é, abbl
4. Àmì
ohùn lórí õrõ onísílébù kan. B.a: bá, dà, kan abbl.
OLÙKÖ
1. Fún
àmì ohùn ní oríkì
2. Śe
àlàyé oríśi àmì ohùn mëtêêta
3. Kô
àwôn fáwëlì pêlú ohùn orí wôn
4. Kô
õrõ onísílébù kan àti ôlöpõ sílébù sára pátákó
5. pè
wön fún akëkõö.
AKËKÕÖ
1. Tëtí
sí àlàyé olùkö lórí oríkì àmì ohùn àti àwôn àmì mëtêêta.
2. Śe
àdàkô fáwëlì àti àwôn õrõ tí olùkö kô.
3. Pe
àwôn fáwëlì àti õrõ náà bí olùkö śe pè wön.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
 • Kádíböõdù tí ó ń śe àfihàn àwôn àmì ohùn lórí
  fáwëlì, õrõ onísílébù kan àti ôlöpõ sílébù.
7.
ÀŚÀ: Ìranra-çni-löwö
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.
Èsúsú
2. Àjô
3. Õwê
4. Àáró
5.
Àrokodóko
6. Çgbë
aláfôwösowöpõ òde òní.
OLÙKÖ
1. Śe
àlàyé oríśiríśi àśà ìranra-çni-löwö àti àýfààní wôn
2. Śe
àlàyé ipò àśà ìranra-çni-löwö nínú iśë àjùmõśe àti ôrõ-ajé
3. Darí
akëkõö láti jíròrò lórí çgbë aláfôwösowöpõ.
4. Kó
akëkõö lô sô ìdí çbu níbi tí wön ti ń jô fôwö-so-wöpõ śiśë
AKËKÕÖ
1. Tëtí
sí àwôn àlàyé olùkö, sì śe àkôsílê kókó-õrõ bí ó ti yç.
2. Śe
ìbéèrè lórí ohun tí kò bá yé e.
3. Kópa
nínú ìjíròrò tí olùkö darí lórí çgbë aláfôwösowöpõ lóde òní
4. Têlé
olùkö lô sí çbu láti lô wo àwôn òśìśë bí wön śe ń śiśë.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1.
Fídíò
2.
Fíìmù
3.
Àwòrán
8.
LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé eré-onítàn
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.
Ibùdó ìtàn
2.
Àhunpõ ìtàn
3. Àśà
tó súyô
4.
Kókó-õrõ
5.
Ìfìwàwêdá
6. Ìlò
èdè
OLÙKÖ
1. Darí akëkõö láti ka
eré-onítàn náà.
2. Śe
ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí eré náà dá lé.
3. Fa
àwôn kókó õrõ yô
4.
Jíròrò lórí êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn
5. Śe
àfiwé ìśêlê inú ìtàn pêlú õrõ tó ń lô láwùjô.
6. Śe
àlàyé lórí ìlò èdè
7. Darí
ìśeré ní kíláásì, ìbá à jë ìran kan àbí méjì
AKËKÕÖ
1. Ka eré-onítàn náà.
2. Ìjíròrò lórí ìśêlê tí
wön ti gbö rí/ kà rí, tí ó fi ara pë èyí tí wön kà.
3. Fa êkö tí wön rí kö yô.
4. Töka
sí oríśiríśi ìlò èdè
5.
Jíròrò lórí àwôn êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn
6. Kópa
nínú ìśeré tí olùkö darí ní kíláásì.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Ìwé
ìròyìn 
2. ìwé ìròyìn tí ìśêlê tó
fara pë ti inú ìwé ti wáyé.
3. fíìmù tó bá eré mu (tí
ó bá wà)
4. Aśô eré
5. Ohun èlò ìśeré
9.
ÀŚÀ: Òýkà ôjö àti ośù ní ilê Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Òýkà
àwôn ôjö tí ó wà nínú õsê. Ìtàn tí ó rõ mö ôn. Ôjö Ajé, Ìśëgun, Ôjörú, Ôjöbõ,
Çtì, Àbámëta.
2. Àwôn
ośù tí ó wà nínú ôdún: Śërë, Èrèlé, Erénà, Igbe, Èbìbí, Okúdù, Agçmô, Ògun,
Ôwëwê, Õwàrà, Belu, Õpç.
OLÙKÖ
1. Śe
àlàyé iye ôjö tí ó wà nínú õsê fún akëkõö
2. Kö
akëkõö láti kô orin tí ó rõmö àwôn ôjö tó wà nínú õsê
3. Śe
àlàyé iye ośù tí ó wà nínú ôdún fún akëkõö.
4. Darí
akëkõö láti kô orin tí ó rõmö àwôn ośù tó wà nínú ôdún.
AKËKÕÖ
1. Tëtí
sí àwôn àlàyé olùkö nípa iye ôjö tí ó wà nínú õsê àti iye ośù tí ó wà nínú
ôdún.
2. Kópa
nínú orin tí olùkö darí ní kíláásì.
3. Śe
àkôsílê ohun tí olùkö kô sójú pátákó sí inú ìwé.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1.
Kádíböõdù tí a kô àwôn ôjö tí ó wà nínú õsê àti ośù tí ó wà nínú ôdún sí.
2.
Káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn ôjö àti ośù sí
10.
ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.
Oríkì aáyan ògbufõ
2.
Ìtönisönà lórí bí a śe ń śe aáyan ògbufõ
3. Śíśe
aáyan ògbufõ çlëyô õrõ láti èdè Gêësì sí Yorùbá
4. Túmõ
gbólóhùn kéèkèèké láti èdè Gêësì sí Yorùbá.
OLÙKÖ
1. Fún aáyan ògbufõ ní
oríkì.
2. Śe àlàyé bí a śe ń śe
aáyan ògbufõ.
3. Śe aáyan ògbufõ çlëyô
õrõ láti èdè Gêësì sí Yorùbá.
4. Túmõ gbólóhùn kéèkèèké
láti èdè Gêësì sí Yorùbá
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí bí olùkö śe ń
túmõ àwôn çyô õrõ àti gbólóhùn
2. Kô àwôn çyô õrõ àti
àwôn gbólóhùn tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
 • Pátákó ìkõwé
 • Śíśe àmúlò àwôn ohun èlò tó wà nítòsí bí i owó,
  àga, omi, pátákó ìkõwé, síbí, abbl
11.
ÀŚÀ: Oúnjç Ilê Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
 1. Oríkì oúnjç
 2. Oríśiríśi oúnjç
 3. Bí a śe ń śe oúnjç kõõkan.
 4. ìsõrí ìsõrí oúnjç afáralókun àti amáradán
 5. Àfiwé oúnjç àtijö àti ti òde òní.
OLÙKÖ
1. Sô oríkì oúnjç
2. Sô oríśiríśi oúnjç
3. Śe àlàyé bí a śe ń śe
oúnjç kõõkan
4. Kô àwôn oúnjç tí ó bö
sí ìsõrí kan náà sójú pátákó
5. Sõrõ lórí àýfààní oúnjç
láti oko àti ewu oúnjç inú agolo
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö.
2. Sô èrò tiwôn lórí oúnjç
3. Kô ohun tí olùkö kô
sójú pátákó sínú ìwé.
4. Ya àtç tí olùkö yà sójú
pátákó.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
 • Oríśiríśi oúnjç tútù
 • Àwòrán
 • Ohun èlò ìśeunjç: ìkòkò, epo, iyõ, irú, ewébê,
  sítóòfù àdògán abbl
12.
ÈDÈ: Gbólóhùn
ÀKÓÓNÚ IŚË
 1. Ìbéèrè
 2. Àlàyé
 3. Àśç
OLÙKÖ
1. Śe àlàyé ìhun õkõõkan
àwôn oríśi gbólóhùn mëtêêta náà.
2. Da àwôn àpççrç tí olùkö
kô sójú pátákó kô sínú ìwé rç
3. Pe àwôn gbólóhùn náà
têlé olùkö
4. Śe àwôn àpççrç mìíràn
yàtõ sí àwôn èyí tí olùkö ti śe
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
 • Kádíböõdù tí a kô àpççrç gbólóhùn ìbéèrè, àlàyé
  àti àśç sí.
13.
ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
14.
ÌDÁNWÒ
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share
Use the search box to search for any topics or subjects that you want