OWE ILE YORUBA (Pry 4 )

Class: Pry four

Subject: Yoruba Studies

Akole:OWE ILE YORUBA

1.Operekete ndagba,inu adamo nbaje adi baba tan inu bi won

  1. Gele o dun bi ka mo we, kamowe ko dabi koyeni,koyeni kodabi kamolo
  2. Omo ti yoo je asamu,kekere lo ti nsenu samusamu

4, Aja ti yoo sonu,kin gbo feere olode

5.Eni ti yoo je oyin inu apata,kin wenu aake

Ise kilaasi
Pari awon owe wonyii

1.omo ti yoo je asamu,____(a) kekere loti nsene samusamu (b)kekere loti salo

2.Aja ti yoo sonu,___(a) a ring jin na (b) ki ngbo feere olode

  1. Eni ti yoo je oyin inu apata,___(a)kin wenu aake (b)a fo apata ni
  2. Ile ti afi to omo,____(a) ategun a gbe lo (b)iri ni yoo wo
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share