MID TERM TEST FIRST TERM YORUBA SS 2

FIRST TERM MID TERM TEST 

                  Subject: YORUBA      Class: S.S 2 Time:

Apa kinni

Dahun gbogbo ibeere 

Ka ayoka isale yii, ki o si dahun ibeere ti o te lee

Ise  agbe se  Pataki. Gbogbo eiyan lo mo ise ribiribi ti awon agbe n se lawujo. Idi ti a fi gbodo mu ise agbe ni okunkun dun iyii. Gege bi a se mo,awon agbe lo n gbin oiruuru ounje ti a n je.  Lai si akitiyan awon agbe, nje enikeni le wa? Ti elomiran ko ba ri ounje je ni oko kan, a dabi eni pe eni naa ko jeun lati bi ojo meta seyin ni.

Bi a  se ni agbe olunje naa ni a ni agbe eleran osin. Iru awon agbe yii amaa sin awon eranko bi maluu, ewure, adiye ati bee bee lo. Awon eranko wonyi  ni a n pa, ti a si fi  se obe eyi ti o n tu eje ati ara wa se.

Oniruuru  aso ti a n wo n  naa je ise owo agbe. Awon lo  n gbin owu ti    a fi n hun  aso .   isori awon           agbe olohun osin naa maa n lo awo eran lati se baagi ati beta ti a le fi se amuyangan ni awujo wa titi lo fi de  oke-okun 

IBEERE

  1. Ewo ninu awon wonyi ni ale fi se bata ____eran(a)Awo (b)Eti (c)Ese (d)Iwo
  2. Kin ni idi ti ise agbe se se Pataki lawujo gege bi alayoka se menu ba a?(a)Gbogbo eniyan lo nilo ise agbe (b) O n je ki agbe le lowo-lowo (c)O n je ki a rowo  fe iyawo (d)O n pese ohun abalaye
  3. Awon agbe a maa sin ohunosin wonyi ayafi(a)Ologbo (b)Maluu (c)Adiye (d)Agutan
  4. Orisii agbe meloo ni alayoka menuba? (a)Okan (b)Meta (c)Meji (d)Merin
  5. Ewo ni a ko le fi owu hun ninu awon wonyi (a)Ankara (b)Apere (c)   Leesi (d)Ofi
  6. “Omo yin looto” le je yo ninu aroko (a)Alalaye (b)Oni leta (c)Alariyanjiyan(d)Asotan
  7. Ninu leta aigbefe ni kan ni a maa n  ko (a)Adiresi (b)Oruko (c)Akori (d)Afiwe
  8. “Ile-iwe mi” je ori oro fun  aroko  (a)Oniroyin (b)Oni leta (c)Alapejuwe(d)Alariyanjiyan
  9. Faweli aranmupe meloo ni o wa ninu ede Yoruba (a)Meje (b)Mefa (c)Marun (d)Merin
  10. Esin ti o wopo julo lawujo Yoruba lode-oni ni (a)Isegun  gbigbe(b)Kirisiteeni (c)Buda (d)Oro
  11. Okan  Pataki lara opo tie sin musulumi duro  le lori ni (a)Ogun jija (b)Itore aanu sise (c)Iku ati ajinde Allah(d)Fifi iya je elesin miran 
  12. Awon____ ni o ko esin Musulumi wo awujo Yoruba(a)Heberu (b)Hausa (c)Giriki (d)Larubawa
  13. Ere idaraya ojumomo ni (a)Okoto tita (b)Alo pipa (c)Ijakadi(d)Ekun meeran
  14. Akoko  wo ni Yoruba maa n saaba se ere idaraya (a)Owuro kutu hai (b)Iyaleta (c)Osan gangan(d)Leyin ise
  15. Awon _____ ni  o ni ege dida (a)Ijebu (b)Oyo (c)Osogbo (d)Egba
  16. Awon ilu wo lo ni oro ayingun? Awon (a)Oyo (b)Ife (c)Ospgbo  (d)Egba
  17. Okan ninu awon wonyi ni a maa n lo oro fun (a)Wiwa Owo (b)Lile ajakale arun ni ilu (c)Lati je ki eto oro aje gbooro si (d)Fun eni ti o n wa omo
  18. Akoko wo ni ale da ega? (a)Osan (b)Owuro (c)Asale(d)Igbakuugba
  19. Okan lara ewi alojunaje-mesin n (a)Ekun iyawo (b)Bolojo (c)Alamo(d)Iyere
  20. Orisa_____ ni o ni arungbe (a)Sago(b)Oro (b)Egungun(d)Oya
  21. Orisa ti o ni iwi kikani(a) Sango (b)oro (c)Egugun(d)Obatala
  22. Gbolohun ti a fi n gbe oro okan kale lori koko kan ni gbolohun (a)Abode (b)Alakanpo (c)Alaye (d)Onisorogbesi
  23. Irufe gbolohun  wo niyi “Gbigba ni won gba  owo ayo ni owo mi ”Gbolohun ”(a)abode    (b)Ase  (c)ibeere
  24. “Pa ilekun de” je apeere gbolohun (a)Abode (b)Ase (c)Alayaye(d)Ibeere 
  25. “Nje oga  ti de    ”gbolohun(a)Abode (b)Ase (c)Alayaye(d)Ibeere

 

  1. “Ki I se olu ni o mu  owo ”je  apeere  gbolohun(a)Abode  (b)Ayisodi (d)alauye(c)ibeere(d)Ase 
  2. Olori awon oyomesi ni (a)Agbaakin(b)Basorun(c)Asipa (d)samu
  3. Oloye Melo ni iwarefa? (a)Marun (b)Mefa (c)Meje (d)Mejo
  4. Oyo ajewo ni oye (a)iyaloja  (b)Iyalode (c)Bobagunwa(d)Ajiroba

APA KEJI

Dahun ibeere meta ni abala yii, sugbon nomba (1) se Pataki 

  1. Ko aroko ti ko din ni 300 eyo oro lori Okan ninu   koko wonyi
  1. Ile iwe ijoba dara ju ile iwe aladani
  2. Omo kunrin wulo fun obi ju omobririn lo
  3. Ojo kan ti n ko le  gbagbe 
  4. Ko leta si olootu iwe iroyin kan ni agbagbe re salaye fun nipa awon ona ti o ti di koto orun  ni adugbo re
  1. Toka si ojuseosugbo marun 

2b. Menuba ohun marun ti a le ri oro se

  1. Meuba opo marun ti o wa iu esin Musulumi

3b. Daruko esin marun ti o wa  ni awujo Yoruba lode oni

  1.  Menuba ise olori ilu marun salaye awon wonyi  
  1. Oba alakoro
  2. Oba alade 
  1. Pelu apeere meji-meji, ki ni 
  1. Gbolohun ase
  2. Gbolohun ibeere
  3. Gbolohun abode 
  4. Gbolohun akanpo
  5. Gbolohun ayisodi

 

 

  

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share