FIRST TERM EXAMINATION PRIMARY 6 YORUBA LANGUAGE

Table of Contents

FIRST TERM EXAMINATION 2020/2021

CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

 

NAME:…………………………………………………………………………………

 

IWE KIKA: IYI ISE SISE: AGBEKE

1.) Ibo ni orisun gbogbo iwa ibaje? (a) Ile-eko (b) Aarin egbe (d) Odede (e) Inu oko

2.) Ewo ni kii se iwa ibaje ninu awon wonyii (a) ole (b) akikanju (d) (e) ojukokoro

3.) Iwa Agbeke di awokose fun awon elegbe re nitori _________

(a) iro pipa re (b) agbagun elubo re (d) iwa omoluabi re (e) iwa awon obi re

4.) Iya Agbeke fun-un ni _________ ko to bere ile-eko

(a) imoran (b) Aso tuntun (d) Ounje to dara

5.) Bawo ni Agbeke se jere iwa re ni ile-eko (a) Won na-an legba (b) won fun-un ise se (d) won fun-un ni eko ofe (e) won da seria fun-un

 

IWE KIKA: IJA KO LERE

1.) Kini Ajao fe se nigba ti Alagba Alao pariwo pe, “omo naa niyi”?

(a) o fe ba ehoro sare (b) o fe salo (d)o mu ehoro kan dani (e) o fe fun won ni ehoro

2.) Won ko pati e bo o, “tumo si pe”

(a) won jaa ni pati e (b) won na-an daadaa (d) won je e niya (e) won fi iya je

3.) Inu Alagba Alao dun nitori won _____

(a) bu Ajao (b) na Ajao (d) fi iya ti ko to je (e) ko won jade

4.) ______ ti Alagba Alao lo ni o je ki won ri Ajao mu

(a) ile-eko (b) ita (d) ogba (e) kilaasi

5.) Oga ile-eko se ileri fun Alagba Alao pe oun yoo ____ (a) doju ti won

(b) sare pe won obi (d) ba gbogbo awon akekoo soro (e) lo si ago olopaa

 

IWE KIKA: EWI OMOLUABI

1.) Ninu ewi yii, a rii pe, omoluabi maa n _____

(a) siwahu (b) so yaya (d) fewo (e) se wobia

2.) Ewi yii koni pe, omoluabi a maa

(a) sepe (b) woso ti ko mo (d) jeun ni won-tunwon si (e) fewo

3.) Omo ti yoo je asamu tumo si (a) omo ti yoo je ologbon

(b) oruko re yoo maa je asomu (d) yoo sa nnkan mu (e) yoo senu samu samu

4.) Akewi yii fe ki a je ________ (a) omoluabi (b) ole (d) wobia (e) gbewiri

5.) Ewi yii so pe:- “a-la-je wora ni _______ (a) ole (b) gbewiri (d) obun (e) wobia

 

 

IWE KIKA: EKE KO NIGBONGBO

1.) Ewi yii je ewi ti o ko ni ni ___________ (a) ogbon (b) iberu (d) ise (e) ife

2.) Ewi yii nki lo pe ki a maa se (a) jale (b) sole (d) korii ra (e) puro

3.) Ewi yii so pe otito (a) Lagbara (b) Ko ni gbongbo (d) soro (e) buru

4.) Ibi ti won fe ki omo fi ogbon naa pamo si ni ____

(a) owo otun (b) inu aso (d) inu oke (e) owo osi

5.) Gbogbo nnkan wonyii ni akewi ni ki a beru afi _____

(a) iku (b) otito (d) arun (e) hilahilo

 

ISEDA ORO ORUKO

(a) Bawo ni a se nseda awon oro oruko wonyii, ni pa lilo afomo ibeere:

ai, oni, ki o ko marun-un marun-un sile, ni apeere:

(1) Oni + isu = onisu

(2) Ai + ku = aiku