Orin Ibile To Je Mo Ayeye Yoruba Primary 5
Class: Primary Five
Subject: Yoruba Studies
Akole: Orin Ibile To Je Mo Ayeye
Week: 4
Term: First Term
Lesson Objectives:
- To understand and appreciate traditional Yoruba songs associated with celebrations.
- To identify and recite the lyrics of various traditional songs.
- To discuss the significance of these songs in cultural practices.
Content:
1. Orin ibile to je mo ayeye igbeyawo:
(a)
Iya mo mi lo, sadura fun mi oo
Iya mo mi lo, sadura fun mi oo
Ki maa mosi, ki ma kagbako nile oko
Ko maa mosi, ki ma kagbako nile oko
Iya mo mi lo, sadura fun mi oo
(b)
Iyawo elese osun, aya wa ni o
Iyawo elese osun, aya wa ni o
E o raya wa bi?
E o raya wa bi?
Eyin te saya yin jati jati
E o raya wa bi.
2. Orin ibile to je mo ayeye ikomojade:
(a)
Kuluubu yeye, oyeye kuluubu
Kuluubu yeye, oyeye kuluubu
A o fotun gbomojo
Kuluubu yeye, oyeye kuluubu
A o fosi gbomo pon
Kuluubu yeye, oyeye kuluubu
(b)
Omo lao fi gbe e e
Omo lao fi gbe ×2
Owo osun lowo awa
Omo lao fi gbe.
3. Orin ibile to je mo ayeye oye jije:
(a)
Borikan ba sunwo arangba oo ×2
Ori teemi sunwo, o ran wo
Borikan ba sunwo arangba.
(b)
Oye o, oye amori baba wa ×2
Baba oloye yii gbayi o gbeye
Oye o, oye amori baba wa.
Review Work:
1.) Daruko marun-un ninu igbese igbeyawo ni aye ode oni.
2.) Se alaye okan ninu won ni ekunrere:
Teaching Method:
- Discussion: Engage students in discussing the meaning and importance of the songs.
- Recitation: Encourage students to recite the songs together.
- Cultural Context: Explain the cultural significance of these traditional songs during celebrations.
Assessment:
- Observation of students during recitation.
- Participation in discussions about the songs.
- Written answers to review questions.