YORUBA PRIMARY 5

Akole: iwe kika Darosa 

  Class: Pry five   Akole: iwe kika Darosa   Ki akekoo tun iwe yii ka ni owo won nile,kiwon si dahun awon ibeere wonyii Lori re Ki won si oju iwe ketaleladorin(73) eko kerindinlogun(16)ninu iwe kika EKO EDE YORUBA ODE ONI.   Ibeere   1.kini o so darosa di olokiki (a)ile ti oko (b)egbe

Akanlo ede ati itunmo rẹ

  Class: Pry five Subject: Yoruba Studies Akole: akanlo ede ati itunmo re   Se aya gbangba! Itumo: ki eniyan doju ko isoro lai beru   Ya apa! Itumo: ki eniyan ma itoju owo tabi ohun ti a fi owo ra   Edun arinle! Itumo: eni ti o ti loeori sugbon ti opa da rago

Akole:OWE ILE YORUBA

  Class: Pry five Subject: Yoruba Studies Akole:OWE ILE YORUBA   Aso koba omoye mo, omoye ti rin ihoho woja   2.Bi okete ba dagba,omu omo re ni yoo mu   Ati gbe iyawo kotejo,owo obe lo soro   4.ile ti afi to mo,iri ni yoo wo   5.kekere lati npeka iroko,toba dagba tan apa

Orin ibile to je mo ayeye.

Date: Friday, 1st May, 2020. Class: Pry five Subject: Yoruba Studies   Akole: Orin ibile to je mo ayeye.   1.) Orin I bile to je mo ayeye igbeyawo: (a) iya mo mi lo,sadura fun mio oo Iya mo mi lo,sadura fun mio oo Ki maa mosi,kima kagbako nile oko KO maa mosi,kima kagbako nile

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 5 SECOND TERM EXAMINATION IWE KIKA DAROSA

SECOND TERM EXAMINATION 2019 CLASS: PRIMARY 5                                                         SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… 1.)   Ko orin ibile kan fun ayeye, eyikeyi ti o ba mo, o le je nibi igbeyawo, nibi isomo loruko tabi nibi oye jije   2.)   Daruko igbese marun-un ninu asa igbeyawo abinibi ki o se alaye okan ninu won IWE KIKA DAROSA

SECOND TERM EXAMINATION PRIMARY 5 YORUBA LANGUAGE

……………………………………………………………………………………      Ko orin ibile kan fun ayeye, eyikeyi ti o ba mo, o le je nibi igbeyawo, nibi isomo loruko tabi nibi oye jije     Daruko igbese marun-un ninu asa igbeyawo abinibi ki o se alaye okan ninu won IWE KIKA DAROSA      Kini so darosa di olokiki? (a) ile ti o

Yorùbá. Ìdánwò ipele kinni odun 201

FIRST TERM EXAMINATION 2017/2018 CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:… DI AWON ALAFO WONYII PELU LETA TI OYE A ________ O ________ Ę ________ G _________ I _________ J ________ L ________ N _________ Ǫ ________ R ________ Ș ________ U _________ Y DI AWON ALAFO WONYII Melo ni iro faweli airanmupe ede Yoruba