Ko okan ninu orin ibile ti o je mo Ayeye SECOND TERM EXAMINATION PRIMARY 5 YORUBA LANGUAGE

SECOND TERM EXAMINATION 2020

CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

1.) Ko okan ninu orin ibile ti o je mo Ayeye

 

2.) Daruko marun-un ninu igbese igbeyawo abinibi ni ile Yoruba, ki o se alaye okan ninu ni soki.

IWE KIKA: DAROSA

1.) Kini so Darosa di olokiki? (a) ile ti o ko (b) eko ti o ko (d) owo ti o ni

2.) Ona wo ni darosa ngba ran mekunnu lowo

(a) o nya won lowo (b) o nfun won ni ise se (d) o nya won nile gbe

3.) Iru iranlowo wo ni darosa nse fun awon akekoo? (a) o nraso ile-eko fun won

(b) o nra aso odun fun won (d) o nfun won ni eko ofe

 

4.) Nibo ni Darosa ti ri owo tire?

(a) nibi ole jija (b) nibi ile ise re (d) nibi jibiti lilu

5.) Darosa nfe ki omode ______

(a) fi oju si eko re (b) feran obi (d) maa sa nile eko

 

IWE KIKA: INA MONAMONA

1.) Kini iru ina ti a nlo, ki ina monamona too de? (a) fitila (b) abela (d) sitoofe

2.) Oruko oyinbo to se awari ina monamona ni _________ (a) lanta (b) wax (d) botinni

3.) Kilo mu ki opopona dabi osan? (a) ina oba (b) fitila (d) lanta

4.) Awon wo lo nse abojuto ina monamona

(a) ajo ile ise olomi ero (b) ajo ile ise ina monamona (d) ajo ile ise abela

5.) Ewo ni o mole ju lara awon ina wonyii: (a) fitila (b) abela (d) ina monamona