AWON OWE ILE YORUBA
AWON OWE ILE YORUBA NIPA ILAANA ALIFABEETI ÈDÈ YORÙBÁ
Òwe leshin ọ̀rọ̀, ọrọ leshin òwe, tí oro bàa sọnù, owe laa má ń fii wàá
( ABD NI PIPA OWE)
A =Aigbofa lanwoke, ifa kan kosi ni para
B = Bami na omo mi, ko denu Olomo
D = Didun lodun labore jeko tile oge t’oge je
E =
Ẹ́ =Egbinrin ote, bati npakan nikan nru.
F = Fifi l’epon agbo nfi koji jabo
G = Gele ko dun bi kamowe, komowe kodabi ko yeni
GB = Gbami gbami ko yagba, Eran nle mibowa kò yẹ ode
H = Hai feso ke ‘boosi, Ni O je ka re ni bani kee
I = Igi gogoro ma gun mi loju, Okere la ti n wo
J = Jakumo kii rin l’osan, eni a bire kin rin rìn dé oru
K = Ko sewu l’oko afi giri Aparo
L = Lala to r’oke nle l’onbo
M = Malu ti ko niru, Oluwa ni nba le esinsin
N = Nini owo eda ko kan agbara
O = Ogodo ti yoo fi’ ni s’esin, gongo imu lo ta
L = le ni Oran seeni wo k’ale meni to feni
P = Paro un niyi, ẹtẹ ni nmuwa
T = Rale, Rale kan k’oni ra Orun
S = Sobiya o to degbo, Onigan laa ke si
S =Sasa eniyan ni nfeni lehin, teru t’omo ni nfeni l’oju eni
T =Teni-teni takisa ni tatan
Iku ti n pa ojugba eni, Owe lo n pa fun ni
W = Wahala ni t’agbe, Olorun lo ni kisu o taloko
Y = Yiyo tí ẹkùn yọọ rìn, kii ṣé tójó
k’ele ekun to jo ko.
The place of Ife in Yoruba History Ife:
Owe Yoruba: 100 Yoruba Proverbs & Their Meanings